Jump to content

Tosin Dosunmu

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

 

Imadu Dooyum
Personal information
OrúkọJaphet Dooyum Imadu
Ọjọ́ ìbí24 Oṣù Kọkànlá 1980 (1980-11-24) (ọmọ ọdún 45)
Ibi ọjọ́ibíNigeria
Ìga1.78 m (5 ft 10 in)
Playing positionMidfielder
Club information
Current clubAkwaUnited F.C.
Senior career*
YearsTeamApps†(Gls)†
1999BCC Lions
2000–2003Lobi Stars F.C.
2004Enugu Rangers
2004–2008Bendel Insurance F.C.
2008–Akwa United F.C.
National team‡
1999–2004Nigeria9(0)
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only and correct as of 21 April 2008.

† Appearances (Goals).

‡ National team caps and goals correct as of 20 May 2002

Tosin DosunmuLL-Q34311 (yor)-Abike25-Tosin Dosunmu.wav Tétísí (tí a bí ní ọjọ́ kẹẹ̀ẹ́dógún oṣù keje ọdún 1980) jẹ́ agbábọ́ọ̀lù ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tẹ́lẹ̀ tí ó gbá bọ́ọ̀lù gẹ́gẹ́ bí agbábọ́ọ̀lù ọwọ́ iwájú .

Àkókò ìgbábóólù Rẹ̀ Nínú Ẹgbẹ́

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Dosunmu gbá bọ́ọ̀lù fún àwọn ẹgbẹ́ agbábóòlù AS Nancy, KV Mechelen, KVC Westerlo àti Austria Wien . Ní àkókò ṣáá ìgbà bọ́ọ̀lù ọdún 2005 sì 2006, ti Dosunmu ń gbá bọ́ọ̀lù fún ikò Beerschot, ó gba oyè agbábóòlù tí ó gba àmì ayọ̀ góòlù méjìdínlógún sì àwòn ní bi Ẹ̀ka Àkọ́kọ́ ikò orí páápá ti Belgian. Won fún ní Orúkọ ìnagije 'Cheadle' nítorí pé ó jọ òṣèré Don Cheadle .

Iṣẹ́ Agbábóólù kárí ayé

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Dosunmu gbá fún ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ní ìgbà èmejì òtòtò ní àgbáyé.

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]