Uche Sherif
Ìrísí
| Personal information | |||
|---|---|---|---|
| Orúkọ | Uche Sheriff | ||
| Ọjọ́ ìbí | 3 Oṣù Kẹ̀sán 1983 | ||
| Ibi ọjọ́ibí | Nigeria | ||
| Playing position | defensive midfielder | ||
| Club information | |||
| Current club | Sharks F.C. | ||
| Number | 6 | ||
| Senior career* | |||
| Years | Team | Apps† | (Gls)† |
| –2005 | Enyimba International F.C. | ||
| 2005–2006 | F.C. Ashdod | ||
| 2006–2007 | Julius Berger FC | ||
| 2008 | Sunshine Stars F.C. | ||
| 2008– | Sharks F.C. | ||
| * Senior club appearances and goals counted for the domestic league only and correct as of November 6, 2006. † Appearances (Goals). | |||
Uche Sherif
Listen (won bí ní ọjọ́ Keta Oṣu kẹsàn-án, ọdún 1983 ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà) ó jẹ́ agbábọ́ọ̀lù ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà tí òun gba lọ́wọ́ lọ́wọ́ fún ikò agbábóòlù Sharks F.C.
Sherif fi ìgbà kan rí gbà bọ́ọ̀lù fún ikò F.C. Ashdod, ni ọrílé-èdè Israel gẹ́gẹ́bi agbábóòlù ọwọ́ èyìn, ní àwọn àkọ́kọò Odún 2005 si 2006. Ó wá sínú ikò F.C. Ashdod láti inú ikò Enyimba International F.C. ni àkókò ṣáá na, Haim Revivo ti ọwọ́ bo ìwé àdéhùn pelu Sherif, Haim Revivo bá jẹ òkan lára àwọn tí wọ́n ní ikò F.C. Ashdod. Ní ìparí ṣáá na,wọn tá Sherif wá sínú ikò Julius Berger F.C. Bakanna ni Oṣu kẹsàn-án ọdún 2008, wọn ta kúrò nínú iko Sunshine Stars F.C. ló sì inú ikò Sharks F.C.
Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ìtọ́kasí Ìta
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Uche Sherif at WorldFootball.net