Jump to content

Ukel Oyaghiri

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Ukel Oyaghiri
Rivers State Commissioner of Women Affairs
AsíwájúJoeba West
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí1964
Ọmọorílẹ̀-èdèNigerian
Ẹgbẹ́ olóṣèlúPeoples Democratic Party
ResidenceNigeria
Alma materRivers State School of Basic Studies, University of Port Harcourt, Rivers State University of Science and Technology, Nigerian Law School.
OccupationLawyer, Politician
ProfessionLawyer

Ukel Oyaghiri (tí a bí ní ọdún 1964) jé̩ agbẹjọ́rò àti olóṣèlú, lé̩ni tó ti sin ìpínlè̩ Rivers rí gé̩gé̩ bí i Alága ìgbìmò fún àwon obìnrin láti odún 2015. Ó rópò Joeba West leni tóti fi igba kan je Ìgbìmò Aláse lábé Gómìnà télè̩rí Chibuike Amaechi.[1]

Oyaghiri lọ si ilé è̩kó̩ alákò̩ó̩bẹ̀rẹ̀ ti ìpínlè̩ Rivers ni ìlú Port Harcourt níbi tó ti gba ìwé è̩rí ẹ̀kọ́ girama (WAEC). Ó ké̩kọ̀ọ́ gboyè B.A.ED. Hons. ní Ilé-è̩kó̩ giga ti ìlú Port Harcourt ní ọdún 1989. Ó gba oyè LL.B. and B.L. ní ilé è̩kọ́ giga tí o n rí sí sáyé̩nsì àti Tẹkinọ́lọ́jì ti ìpílè̩ Rivers àti ni Ilé-È̩kó̩ Aṣòfin lé̩sẹẹsẹ.

Ó ṣiṣé̩ gé̩gé̩ bí i Olùrànló̩wó̩ àkọsílè̩ àjọṣepò̩ (public relations assistant ) ní ié iṣé Rivbank Insurance láti odún 1989 títí di 1990, O tún jẹ́ Olùṣàkóso gbogbogbò ni ilé ìwòsàn Pamo láti odún 1990 títí di 1997, Ó̩ tún je amúgbálé̩gbẹ̀é̩ sí Kọmíṣánnà lórí ètò è̩kó̩ ti ìpínlè̩ Bayelsa ní ọdún 1997 sí 1998 àti òṣìṣẹ́ òfin ni ilé iṣé̩ oníṣé̩ òfin Adedipe & Adedipe láti o̩dún 2004 si o̩dún 2007. Ó tún jé̩ adarí amòfin fún A.S. Oyaghiri & Associates Legal Practitioners láti ọdún 2011, títí wón fi yàn án gé̩gé̩ bí i kọmíṣánnà fún ètò àwo̩n obìnrin ní Oṣù kejìlá ní o̩dún 2015.

Àwọn ipò mìíràn tó dìmú

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  • Alága Ẹgbé̩ Taekwondo ti ìpínlè̩ Rivers (1996–1998)
  • Igbá kejì Alága ẹgbé̩ Taekwondo ti Orílẹ̀ ède Nigeria (1993–1996)
  • Ààre̩ fún ẹgbẹ́ẹ Obìrin Orashi àti akò̩we fún àwọn àgbaagbà, aṣojú fún ọmọ ẹgbẹ Orashi

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "Barr. Mrs. Ukel Oyaghiri". Riversstate.net.ng. Archived from the original on 1 September 2016. Retrieved 21 September 2016.