Jump to content

Valerio Alesi

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Valerio Alesi
Personal information
Ọjọ́ ìbí5 Oṣù Kẹ̀sán 1966 (1966-09-05) (ọmọ ọdún 60)
Ibi ọjọ́ibíHamilton, Ontario, Canada
Senior career*
YearsTeamApps†(Gls)†
1984–1985Ascoli2(1)
1985-1986Unknown
1986-1987Civitavecchia?(?)
1988-1989Bolzano?(?)
1989-1990Acri?(?)
1990-1992Fermana?(?)
1992-1993Maceratese?(?)
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only.
† Appearances (Goals).

 

Valerio Alesi (tí a bí ní ọjọ́ karùn-ún oṣù kẹsàn-án ọdún 1966) [1] ọmọ ilẹ̀ Canada ni, ó sì jẹ́ agbábọ́ọ̀lù alágbàṣe tẹ́lẹ̀ ní Ítálì.[2]

Alesi gbá bọ́ọ̀lù méjì ní Serie A nígbà tí ó dara pọ̀ mọ́ Ascoli Calcio ní ọdún 1984. Lẹ́yìn àkókò kan ṣoṣo pẹ̀lú Ascoli, ó dara pọ̀ mọ́ àwọn ẹgbẹ́ ìdíje ìsàlẹ̀ títí di ìparí ọdún 1990.

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Page Àdàkọ:Reflist/styles.css has no content.

  1. ↑ Empty citation (help)
  2. ↑ "Valerio Alesi". worldfootball.net. Retrieved 2021-11-26.