Jump to content

Venita Akpofure

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Venita Akpofure
Ọjọ́ìbí1987
Britain
Orílẹ̀-èdèBritish-Nigerian
Iṣẹ́
  • Actress
  • Video vixen
Gbajúmọ̀ fún
Olólùfẹ́Tena Terka (div. 2019)
Àwọn ọmọ2


Venita Akpofure (tí a bí ní ọjọ́ kínní, oṣù kínní, ọdún 1987) Big Brother Naija (season 4)[1] jẹ́ òyìnbó-alawo dúdú British-Nigerian tó sì jẹ́ òṣèré amóhùnmáworan. [2]ó jẹ́ gbajùmọ̀, ìlú mòoká lẹ́yìn tí ó jáde nínú ilé Ẹ̀gbọ́n àgbà ìran ẹlẹ́ẹ̀kẹrin tí ayé mọ̀ sí Big Brother Naija Season 4 tí ó jé ara inú naa. Ò sí jẹ́ akópa nínú eré ojú èrò amóhùnmáworan orí AFRICA MAGIC tí àkọọlẹ rẹ jẹ́ UNMARRIED, èyí tí ó sí jẹ́ OLÚ ÒṢÈRÉ inú eré naa.

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. ↑ Augoye, Jayne (10 May 2020). "INTERVIEW: My Role in 'Unmarried' series and life after BBNaija – Venita Akpofure". Premium Times.
  2. ↑ Nwogu, Precious (20 January 2021). "'Unmarried' returns for its 2nd season this January". Pulse NG. Archived from the original on 22 November 2022. Retrieved 18 March 2022.