Victor Ezeji
Ìrísí
| Personal information | |||
|---|---|---|---|
| Ọjọ́ ìbí | 9 Oṣù Kẹfà 1981 | ||
| Ibi ọjọ́ibí | Rivers State, Nigeria | ||
| Ìga | 1.74 m (5 ft 81⁄2 in) | ||
| Playing position | Striker | ||
| Senior career* | |||
| Years | Team | Apps† | (Gls)† |
| 1996 | Sharks F.C. | ||
| 1997–1999 | Eagle Cement | ||
| 2000–2002 | Sharks F.C. | ||
| 2003 | Enyimba F.C. | ||
| 2004–2007 | Dolphins F.C. | ||
| 2007–2008 | Club Africain | ||
| 2008–2012 | Sharks F.C. | ||
| 2013–2014 | Enyimba FC | ||
| 2014–2015 | Sunshine Stars FC | ||
| 2015–2015 | Heartland FC | ||
| National team | |||
| 2004 | Nigeria | 3 | (2) |
| * Senior club appearances and goals counted for the domestic league only and correct as of 8 May 2014. † Appearances (Goals). | |||
Victor Ezeji fetisi ⓘ (tí a bí ní ọjọ́ kẹsàn-án oṣù kẹfà ọdún 1981) jẹ́ agbábọ́ọ̀lù ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí ó gbá bọ́ọ̀lù kẹ́yìn fún Crown FC Ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn agbábọ́ọ̀lù tí ó ṣe àṣeyọrí jùlọ àti tí ó pẹ́ jùlọ ní aumọṣe bọ́ọ̀lù Nàìjíríà. Ó gba ife-ẹyẹ Ajumọṣe Awọn aṣaju-ija Afirika meji pelu egbe agbaboolu Enyimba, Aba, Ipinle Abia, Nàìjíríà.
Àgbáyé
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Agbábọ́ọ̀lù náà gbá bọ́ọ̀lù ní ìdíje mẹ́jọ fún Super Eagles.
Àwọn Àkíyèsí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Page Àdàkọ:Reflist/styles.css has no content.