WP:TWLY

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search

àárin Yàrá ìkàwé Wikipédíà

Yàrá ìkàwé Wikipédíà n Ìràn Akọ̀wé lati láánfàní sí àwọn ojúlówó orisun tí a fi n kọ Wikipédíà dára dára.

A tún n ran àwọn akọ́sẹ́mọsẹ́ lati jẹ́kì gbogbo ayé láánfàní sí àwọn àkọsílẹ wọn.


Báwo lase lè ràn ẹ́ lọ́wọ́?

State Library of Victoria La Trobe Reading room 5th floor view.jpg
Wikipedia Library owl.svg Iyàrá ìkàwé Wikipédíà


WP:TWLY
Darapò kí o lè ní ànfàní WP:TWLYAlámójútó ìforúko sílè: Ikò iyàrá ìkàwé Wikipedia - forúko sílè kí o lè sèrànwó!

Wikipedia:WP:TWLY/Navbox


Àwon ohun tí o nílò[àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

 • O nílò email tí ó n sisé láti lè ma gba lẹ́tà láti orí Wikipedia Gèẹ́sì tàbí lórí Wikipédíà èdè abínibí tí o yàn láàyò tó dá lórí àsàyàn re; (wo Special:Preferences)
 • O ti gbọ́dò dara pò mọ́ Wikipédíà fún osù mẹ́fà tàbí ọdún kan 6 osù mẹ́fà.
 • O ti gbọ́dò kọ àyokà tí ó tó egbèrún kan tàbí500 ogórùún sórí ìwé ìmọ ọfé.
 • O kò lè ní ànfàní láti lo orísun ìmọ nípa Iyàrá ìkàwé mìíràn tí ó yàtọ sí ti Wikipédíà bí o kò bá pegedé tàbí ní ìmọ tó lọọrìn tó, àmó o sì lè jé olùkópa tí ó dára jùlo bí o bá forúkọ sílè. Fúndí èyí, má jáfara láti forúko sílè

Àwon àfojúsùn[àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àwon ònkòwé tí a fowósí lè se ìwònyí

 • Sewádìí, gbéyèwò, gbà padà, àti láti tú àwon àkosílè tí a fòté lé;
 • Ó lè fi àwon àkosilè tí a fòté lé pamó;
 • Ó lè sàtèjáde lára àwon àkosilè tí a fòté lé pamó;

Àwon ònkòwé tí a fowósí kò ní lè se ìwònyí

 • Kò lè fún tàbí ta orúko onísé àti òrò ìpamó rè fún enìkéni ní.
 • Kò lè sàrù sílè àkosílè lópò yanturu WP:TWLY;
 • Kò lè se àtèjáde tàbí kí ó lo èro kan láti kó pamó lópò tàbí labala sórí èró kankan lábé bí ó ti wù kí ó rí.
 • Kò lè kowó bo metadata láì gba àse lílò rè, fún àpeere, kí ó lòó láti fi sèdá àkosílè tí ó ní èdà (stub) nínú.
 • Kò gbodò tàpá sí òfin àti ìlànà kan kan tí ó je mó ojú ewé tí ó bá n gbé yèwò lówó WP:TWLY.

Òrò Ìkòkò àti àsírí

 • Bí o bá ti dara po mó ètò wa, oní láti mò kí o sì gbà wípé o lè sàfihàn orúko, àti àwon àkójo òrò inú email re pèlú àwon asojú àjo Wikimedia,iyàrá ìkàwé Wikipédíà, àti WP:TWLY.Àwon elétò iyàrá ìkàwé Wikipedia tí wón dòwò pò kábé àse àjo Wikimedia ní láti tèlé ìlànà ìpamó àjo Wikimedia tí wón jo fowó sí. Olù farajìn (Volunteer) tí ó n sójú iyàrá ìkàwé Wikipédíà kan kan kìí se òsìsé tàbí olúbá-dòwòpò àjo Wikimedia (or WP:TWLY), sùgbón wón ti kowó bòwé àdéhùn tí ó lágbárá láti lè tójú àsírí tí àjo Wikimedia fi pamó sí won lówó.

Ìdárúko[àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

 • Onísé ní láti dárúko tó fesè múlè tí ó le funi ní èkúnréré ìmò bí wón bá n so orísun òrò pò WP:TWLY WP:V àti ibibtí wón ti rí irúfé orúko béè WP:SAYWHEREYOUGOTIT.
 • Onísé kò ní láti fi ìsopò òfo sí àkosílè tàbí ojú ewé tí a fòté lé WP:TWLY.
 • Kíèsi (subscription required) nínú orúko nibibtí ó bá ye.
 • Bòwò fún ofin ìwé kíko (copyright) WP:TWLY, ní ìbámu oèlú ìlànà, òfin àtí àmúse-múlòtí Wikipédíà gbé kalè.
 • Sàfihàn orísun níbàmu pèlú ìlànà àpeere ìdárúko tí wón ti oèsè sísàlè yìí WP:TWLY
Kíèsí àgbékalè orúko àwon àkosílè yàtò síra won; oníse lè lo ìrísí tí ó bá dára fún àkosílè níwòn ìgbà tí ó bá ti fesè-múlè tí ó sì pé.


Fún ìkópa[àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

O lè ran iyàrá ìkàwé Wikipédíà lówó láti tan ìfowó-sowópò ká:

 • Sàfikún {{Wikipedia:WP:TWLY/Userbox}} sí àpótí onísé re. Èyí ni yóò ràn wá lówó láti se ìtànká isé àkànse wa pèlú àwon onísé tí wón ti lóye.

Wikipedia:WP:TWLY/Userbox


Àdàkọ:TWLJ


Àdàkọ:Cquote Àdàkọ:Cquote Àdàkọ:Cquote Àdàkọ:Cquote Àdàkọ:Cquote