Jump to content

Willy Kalombo Mwenze

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Willy Kalombo Mwenze (tí wọ́n bí ní ọjọ́ keje oṣù kẹfà ọdún 1970) jẹ́ asáré ìjìnnà gígùn tí ó ti fẹ̀yìntì láti ori Democratic Republic of Congo tí ó jẹ́ ògbóǹtarìgí nínú ìdíje marathon . Ó lọ sí eré ìdíje Olympic ní emẹ́ta (1992, 1996, 2000).

Ó parí ní ipò kẹrinlá nínú ìdíje àgbáyé ọdún 1997 àti ní ipò kọkàndínlọ́gọ́ta nínú ìdíje àgbáyé ọdún 1999 . Ó tún gba àmì-ẹ̀yẹ fàdákà nínú ìdíje African Marathon Championships ti ọdún 1996 [1] . Àkọsílẹ̀ Àkókò eré rẹ tó dára jùlọ ni wákàtí 2:08:40, èyí tó dé ní oṣù kẹrin ọdún 1999 ní Paris. Àkọsílẹ̀ àkókò eré rẹ òun ni ó jẹ́ ti orílẹ̀-èdè yìí nìyí lọ́wọ́lọ́wọ́.[2]

Àkọsílẹ̀ àwọn àṣeyọrí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àdàkọ:Unreferencedsect

  • All results regarding marathon, unless stated otherwise
Gégébí aṣojú fún Àdàkọ:ZAI
1992 Olympic Games Barcelona, Spain – 5000 metres DNS
1992 Olympic Games Barcelona, Spain 50th 2:23:47
1996 Olympic Games Atlanta, United States 16th 2:17:01
Representing  Democratic Republic of the Congo
1997 World Championships Athens, Greece 14th 2:19:18
1999 World Championships Seville, Spain 49th 2:31:55
2000 Olympic Games Sydney, Australia — DNF
2003 World Championships Paris, France — DNS
  1. ↑ World and Continental Road Race Championships and Cups – GBR Athletics
  2. ↑ Congolese athletics records