Zainab Abubakar Alman
Ìrísí
Zainab Abubakar Alman jẹ́ ọ̀kan lára akẹgbé̩ ilé-gbìmọ̀ asòfin tẹ́lẹ̀ rí ní ìpìnlẹ̀ Gombe, àti olùdarí àgbà fún e̩gbé ìdàgbàsókè awùjo̩ àwọn obìnrin (ARC-P) lábé̩ ìṣàkóso Muhammad Inuwa Yahaya.
Ìbẹ̀rẹ̀ ayé àti ètò-ẹ̀kọ́
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Wó̩n bí Alman ní ọjọ́ kẹrìnlá oṣù kinní, ọdún 1964,ní ìjọba ìbílẹ̀ Kaltungo ti ìpínlẹ̀ Gombe. ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ gbogbo nìse níbi tí ó ti gba ìwé ẹ̀rí àkọ́kọ́ ti ìdàgbàsókè àwùjọ ní ìpínlẹ̀ Kaduna ní ọdún 1991[1]
Iṣẹ́
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Alman ṣiṣé̩ pẹ̀lú ìgbìmọ̀ Iṣẹ́ Abélé ti ìpínlè̩ Gombe gẹ́gẹ́ bi alákòóso ìdàgbàsókè àgbègbè, Oluyèwò, àti olórí apakan laarin 1987 ati 2000.
Awon Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Muhammad, Wala (2007). Gombe State House Assembly: The second coming. Gombe. pp. 1–10. ISBN 978-9783485594.