Jump to content

Zainab Ahmed

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Zainab Ahmed

Minister of Finance, Budget and National Planning
In office
21 August 2019 – 29 May 2023
ÀàrẹMuhammadu Buhari
Minister of StateClement Agba
AsíwájúHerself (as Minister of Finance)
Udoma Udo Udoma (as Minister of Budget and National Planning)
Arọ́pòWale Edun (as Minister of Finance)
Abubakar Atiku Bagudu (as Minister of Budget and Economic Planning)
Minister of Finance
In office
14 September 2018 – 28 May 2019
ÀàrẹMuhammadu Buhari
AsíwájúKemi Adeosun
Arọ́pòHerself (as Minister of Finance, Budget and National Planning)
Minister of State for Budget and National Planning
In office
11 November 2015 – 14 September 2018
ÀàrẹMuhammadu Buhari
AlákósoUdoma Udo Udoma
Arọ́pòClement Agba
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí16 Oṣù Kẹfà 1960 (1960-06-16) (ọmọ ọdún 65)
Ẹgbẹ́ olóṣèlúAll Progressives Congress
Alma mater
Occupation
  • Politician
  • accountant

Zainab Shamsuna Ahmed tí a bí ní ọjọ́ kẹrìndínlọ́gún oṣù kẹfà jẹ́ oníṣirò ilẹ̀ Nàìjíríà [1] àti òṣèlú, tí ó sì jẹ́ mínísítà fún ètò ìṣúná owó, Budget ilẹ̀ Nàìjíríà [2][3] láti ọdún 2019 sí 2023. Ó ti kọ́kọ́ fi ìgbà kan jé mínísítà fún owó rí láti ọdún 2018 to 2019, gẹ́gẹ́ bí ó sì ti jẹ́ pé òun náà ni ó ń ṣàkóso ètò ìṣúná owó láti ọdún 2015 sí 2018.[4][5] ní 2019, olórí-orílẹ̀-èdè Muhammadu Buhari pa ìṣàkóso méjèèjì náà pọ̀ sí ọ̀kan, tí ó sì fi ṣe aṣoju ètò ọrọ̀ ajé lápapọ̀.[1][6]

Oníṣẹ́ ìṣirò, ẹni tí ó kàwé gboyè (Bachelor of Science degree) nínú iṣẹ́ ìṣirò ní ABU Zaria tí ó tún tèsíwájú nínú ẹ̀kọ́ tí ó tún gboyè Master's nínú ìṣàkóso okòòwò (Business Administration) (MBA), Ahmed gba ipò Finance Minister ẹ́yìnKtí ẹni tí ó wà nibẹ̀ parí iṣẹ́ ìyẹn emi Adeosun oní 4 September 2018.[7]

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. 1.0 1.1 Oladeinde Olawoyin (September 17, 2018). "Zainab Ahmed: The official overseeing Nigeria's finance ministry". Premium Times (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on Sep 17, 2018. Retrieved 9 August 2023.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  2. "'Minister's approval of TAT rule at variance with enabling Act'". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2021-10-14. Retrieved 2022-02-22. 
  3. Ayitogo, Nasir (21 August 2019). "Buhari assigns portfolios to new ministers". Retrieved 2 September 2019. 
  4. "The CVs of Buhari's ministers at a glance". PM News. Retrieved 12 November 2015. 
  5. "Nigeria is the hub of stolen cars – Finance Minister, Ahmed Zainab". Naijalitz. 13 August 2021. Retrieved 13 August 2021. 
  6. "Zainab Ahmed". World Bank Live (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2024-01-22. 
  7. "Buhari accepts Adeosun resignation, names Zainab Ahmed as replacement". Cable. 14 September 2018. Retrieved 14 September 2018.