Femi Kuti

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search
Femi Kuti
Photo by Tom Beetz
Photo by Tom Beetz
Background information
Orúkọ àbísọFemi Anikulapo Kuti
Ìbẹ̀rẹ̀London, UK/Nigeria
Irú orinAfrobeat, jazz
Occupation(s)Singer-songwriter, instrumentalist
InstrumentsSaxophone, vocals, trumpet, keyboards
Years active1978 - present
Associated actsEgypt 80, Positive Force

Olúfẹlá Olúfẹ́mi Aníkúlápó Kútì (ọjọ́ìbí 16 June 1962) jẹ́ olórin ọmọ orílẹ̀-èdè Naijiria. Gbajúgbajà akọrin yí ni a mọ̀ sí Fẹ́mi Kútì. Ó jẹ́ akọrin ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí a bí ní ìlú London tí ó dàgbà sí ìlú Èkó. Ó jé àkọ́bí ọmọ ọkùnrin ọmọ bíbí olùdásílẹ̀ orin Afrobeat tí a mọ̀ sí Fẹlá Kútì àti ọmọ ọmọ akíkanjú olóṣèlú, ajá fún ẹ̀tọ́ àwọn obìnrin, ìyá ààfin Olúfúnmiláyọ̀ Ransome-Kútí.Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]