Atúmọ̀-Èdè (Gẹ̀ẹ́sì-Yorùbá): F

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Atumo-Ede (English-Yoruba): F

Oju-iwe Kiini[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

fable: n; (His fable was very interesting.) ìtàn asan. Ìtàn asán rè dùn gidigidi.


face: n; (The ball hit him in the face.) ojú; iwájú. Bóòlù náà bà a ní iwájú

face:v;  (They  faced each other.) dojú ko wón dojú ko ara won. 

fact: n; òtító; ohun tí ó dájú gan-an kó sí eni tí ó lè ta ko òtítóo náà pé iná máa n jò.

factory: n; (No one can deny the fact that fire burns.) (He has car factory.) ilé-isé ó ní ilé-isé ìse okò.

fade: v; (The sun has faded these curtains.) (The crowd began to fade away.) bó; sá. Oòrùn ti jé kí àwon aso ikélé yìí sa. Dún ku; lo díèdíè Àwon èrò bèrè sí ní dún kù

faggot: n; (He carried the faggot on his head.) erù igi; ìdì igi ó gbé ìdì igi náà lé orí.

fail: v; (He never fails to write to his mother every week.) (She promised that she wouldn’t fail him.) (The power began to fail as soom as I switched the machine.) kùnà; já kulè kì í kùnà láti kòwé sí ìyáa re lósòòsẹ̀ já ní tànmóò; já kulè o se lérí pé òun ko ní jáa kulè. Tàsé. Iná náa bèrè sí ní tàsé ní géré tí mo tan èro náà.

failure: n; (All my efforts ended in failure.) ijákulè; ìkùnà. Gbogbo ipá mi ló já sí ijákulè.

faint: adj; (His breathing become faint.) tí i tí dínkù jòjo. Èémí re ti dínkù jojo.

faint: v; (He fainted from hunger.) dákù. Ebi mú un dákú.

fair: adj; (All her Children are fair.) dára; léwà. Gbogbo àwon omo rè ló dára.

fair: adv; (They will respect you as long as you play fair with them.) lónà tí ó tó. Won yóò ni ìteríba fún o níwòn ìgbà tí o ba n se nnkan lónà tó tó pèlú won. 

fair: n; (He took the Children to the fair.) ìpàte gbangba, ó kó àwon omo náà lo sí ini ipàte gbangbe náà.

fairly: adv; (It is fairly good.) ní ìba ; ní ìwon, ó dara ni wòn.

fairy: n; (There are many wicked faires in this world.) egbéra; iwin. Awon iwin/ egbére tó búrú pò laye yìí.

faith: n; (He puts his faith in God.) ìgbàgbó ó ní ìgbàgbó rè nínú olórun.

faithful: adj; (He remains faithful to his wife.) olódodo; olóòtó ó jé olódodo sí aya re.

faithfully: adv; (I followed the instruction Faithfully.) pèlú òdodo; nínú òdodo. Mo tèlé àwon ìlàná náà pèlú ododo.

fake: adj; (He has a fake jewellery.) àdàmòdì; ayédèru ó ní ayédèru ohun òso kan.

fake: v; (He faked his father’s signature. se ayéderú ó se ayédèrú bí bàbá re ti se máa n fowó si ìwe.

fall: n; (I had a fall and broke my arm.) (There was a fall in prices.) ìsubúlulè; ìyílè; ìjálulè mo ní subululè mo sì ti apá mi kan. Idínkù ; ìlosílè Idínkù wà lórí owo ojà.

false: adj; (He brought false accusation against her.) èké; tí kò jé òdodo ó fi èsùn kàn án pèlú eké.

falter: v; (For a moment he faltered in his purpose.) bóhùn. Fún ìgbà kan, ó bóhùn lór ilàkàkà rè.

familiar: adj; (There are familiar face here.) (There was something familiar about him.) mímò. Àwon ojú mímò wà nibi. Mó lára Nnkan kan wà tó mó on lára.

family: n; (They are all in the same family.) ebí; ìbátan; ìdílé. Ebí kan náà ni gbogbo won.

famine: n; (The prolong drought was followed by months of severe famine.) ìyàn. Àsìkò ògbebe tó pé náa jé kí ìyàn ti ó le mú fún òpolopò osù.

famished: adj; (When is the launch? I am famished.) kú fún ebi. Nígbà wo ni oúnje òsán? Mo n kú fún ebi.

famous: adj; (She is more famous as a writer then as an actress.) gbajúmò; lókìki ó lókíkí gégé bí onkòwé jú bí òsèré lo.

fan:n; (He bought a new fan.) (I was in the amidst of the crwds of football fans.) abèbé ó ra abèbè tuntun. Olólùfe. Mo wà láàrin àwon èrò tí wón jé olólùré aré bóòlù aláfésegbá.

fan: v; (He fanned himself with a newspapar.) (His reluctance to answer her question simply fanned her curiousity.) fé atégùn sí ó fi ìwé ìròyìn fé atégun sí are rè. Ru sókè Aif;e dáhùn ìbéèrè rè ìtára rè soke.

fancy: n; (They are all night-time fancies that disappear in the morning.) ìsebí; ìrò; èrò. Àwon ero àsálé tí o máa n pare ní aaro ni gbogbo won. fancy: adj; (The kitchen was full of fancy gadgets.) tí o jujú ní gbèsè. Awon ohun èlò ilé tó jojú ní gbèsè kun ìnu ilé ìdáná náà.

fancy: v; (She didn’t fancy the idea of going home in the dark.) fé; fé láti se kò fé ìwa lílò sílé nínú òkùnkùn.

fang: n; (The fangs in the dog’s mouth are long.) eyín tí o ta jáde lénu. Awon eyín tó ta jáde ní eyín enu ajá nàá gun.

far: adv; (The restaurant is not far from here.) jìnà Ilé oúnje náà kò jìnà sí ibí.

fare: n; (When do they start paying full fare?) owó okò yóò. Nígbà wo ni wón yóò bèrè sí ní san owó okò won pé?

fare: v; (The party fared very badly in the last election.)  se dáádáa/ se àìse dáádáá. Egbé òsèlú náà ko se dáadáa nínú idìbò tó  koja.

fare-well: n; (She said her fare-wells and left.) òrò ìdágbere ó so àwon orò ìdágbére rè o sì lo.

farm: n; (My father has a pourltry farm.) oko Baba mi ní oko adìye ken.

farmer: n; (My father is a poultry farmer.) àgbè. Agbè aládìye ni bàbá mi.

farm-yard: n; (The man is working in his farm-yard.) ogbà oko. Okùnrìn náà n sise nínú ogbà oko rè.

farther: adv; (I can’t go any farther.) síwáju. N kò lè sún síwáju mó

farther: adj; (The farther shore of the lake is high.) tí o wà níwáju; òpin opin bèbè adágún odò náà ga.

facinate: v; (China has always facinated me.) fà mórà Orílè-ede ‘china’ti máa n fà mí móra.

fascinated: adj; (I have always been fascinated by his ideas.) ní ìfanimóra mo máa n ní ìfanimóra pèlú àwon ìwa rè.

fascinating: adj; (They story was very fascinating.) tí ó fani móra. Ìtàn náà fani móra dáadáa.

fast: adj; (He is a fast reader.) ti ó yára; yá ó yára ní iwé kika.

fast: adv; (I can’t go any faster.) yara; sáré. N kò lè sare/yára jù báyìí lo.

fastening: n; (The trousers have a fly fastening.) ìso; bí a ti so nnkan pò Àlàfo wà láàrin ibi ti a ti so sòkòtò náà.

fat: n; (He cooked the meat in a shallow fat.) òrá ó se eran náà nínú òrá díè.

fat: adj; (He is a big fat man.) sanro o jé okùnrin to tóbí tó sì sanra.

fatal: adj; (If you get ill again it could prove fatal.) ti n pa ni; tí o n fa ikú. Tí o ba se àìsàn sí ó lè fa ikù.

father: n; (Our new boss is a father of three.) bàbá, Ogá wa tuntun jé baba fun omo méta

father: v; (He claims to have fathered over 20 Children.) se baba fún ó gbà pé òun ti se baba fún ogun omo.

fault: n; (It’s your own fault for being cereless.) èbi; àsise; àbùkù. Èbii re ni àìjáfáfá rè.

fault: v; (He had alwys been polite-she couldn’t fault him on that.) dá lébi o máa n se dáadáa kò lè dáa lébi lórí ìyen.

favour: n; (I would never ask for any favours froms her.) ojú rere; ìseun. N kò ní bèère fún ojú rere lódò rè.

favour: v; (His standing with me favoured me.) se ojú rere fún; jínkí sànfààní fún Dídúró tí ó dúró tì mi se Ànfààní fún mi.

favourable: adj; (She made a favourable impression on his parents.) dùn móní ó so ohun okan to dùn móni lórí àwon obíi rè.

favourite: n; (Who is your favourite writer?) olólùfé ònkòwé wo ni olólùfé re?

favouritism: n; (The students accused the teacher of favouritism.) ojúùsàjú Àwon akékòó náà fi èsùn ojúùsàjú kan olùkó náà.

fawn; n; (The hunter caught alive fawn.)omo àgbònrín ode náà mú omo àgbònrin kan laaye.

fear: n; (The Child was shaking with fear.) èrù ìbèrubojo; ìfòyà omo náà n gbòn pèlú èrù.

fear: v; (All his employees fear him.) bèrù, Gbogbo àwon òsìsé rè ló bèrù rè.

fearful: adj; (Parents are ever fearful for their Children.) níbèrù; nífòyà Àwon òbí máa n ní ìbèru nítorí àwon omo won.

fearless: adj; (He is a fearless man.) láìní ìbèrù; láìní ìfòyà ó jé aláìníbèrù okùnrin.

fearsome: adj; (The man is very fearsome.) ní èrù; tí o bani lérù okunrin náà bani lérù gidigidi.

feast: n; (They went to the wedding feast.) àsè; àpeje. Wón lo sí ibi àsè ìgbáyàwó náà.

feast: v; (He feasted on rice.) je òpòlopò ounje pèlú ìgbádùn o je òpòlopò ìresì pèlú ìgbádun.

feather: n; (He gave me a peacock feather.) ìyé eye ó fún mi ní ìyé eye òkún.

feat: n; (He performed astonishing feats) isé agbára ó se isé àwon agbára tó yani lénu.

feable: adj; (He is a feeble old men.) láìlera; láìlágbára. Ó jé arúgbó okùnrin aláìlágbára.

feed: v; (Have your fed the cat yet?) fún lóúnje N je o tíì fún olóngbò náà lóúnje síbè?

feel: v; mò; (She felt a hand on his shoulder.) mò lára ó mò pé a gbé owó kan lé oun.

feet: n; (Rise no your feet.) ese méjèèjí Dìde lórí èsè re méjèèjì

fellow: n; (He has a very good reputation among her fellows.) elegbe; èni kejì ó ní ìyìn rere láàrin àwon elegbé rẹ̀

felt: n; (He gave me a felt hat.) aso onírun o fún mi ní fìlà tí a fi aso onírun se.

feminine: adj; (That dress makes you look.very feminine:n;) (The teacher taught the student feminine gender.) ajemábo. Aso jé kí o dà bí obìnrin dáadáa. nnkan to je mó ìmabo Olùkó kó àwon akékòó náà ní àwon ohun to jé mo ìmabo yàtò.

female: n; (She is a female student.) abo;obìnrin Akékòó obìnrin ni

festival: n; (Christmas and Easter are the main Christian festivals.) àjòdun, ìgbà àsè odún kérésìnesì àti odún àjínde jé àwon àjòdún omoléhùn jésu to se pàtàkì jù.

fetch: v; (She has gone to fetch the kinds from school.) mú wá; gbé wá ó ti lo gbe àwon omo náà wá láti ile-iwé.

fete: n; (The village fete was very interting.) eré ìtagbangba- àwon eré ìtagbangba tí a sètò láti pawó wolé fún àwon idí kan.Eré ìtagbangba abúlé náà dùn púpò.

fever: n; (He has a high fever.) ibà Ako ibà n se é.

few: adj; (Few people understand trhe difference. díè Àwon ènìyàn díè mo ìyàtò náà

few: pro; (Few of the books are worth reading.) díè Díè nínú àwon ìwé náà se é kà

fib: n; (Stop telling fibs.) iró. Dakee iró pípa

fib: v; (Come on, don’t fib! Where were you last night.)pa iró; so eké wá, má paró ; Níbo lo wà lálé àná?

fiction: n; (He narrated a romantic fiction.) ìtan kàyéfì ó sa ìtan kayefi ajemo ifé.

fiddle: v; (He was fiddling with the key as he while he talked to me.) (He fiddled the accounts.) (He was fiddling.) fi sere pèlú owó ó n fi kókóró náà sere lówó bí ó ti n ba mi sòró.Yí- O yí iwé ow;ó náà. Fi ohun-èlo orin bíi fere tabí dùùrù seré o n fi dùùrù seré.

fiddle: n; (The priest bought a violin.) irufé dùùrù kan Àlùfáà náà ra irúfé dùùrù kan.

fiddler: n; (The man is a fiddler.) eni tí o n fi irúfé dùùrù kan seré Okùnrin náà máa n lu irufe dùùrù kan.

fidget: v; (Sit still and stop fidgeting.) rún are; sàifara balè Jókòó jéé, ma rúnra mó.

fidget: n; (The Child is a complete fidget.) eni tí kú farabale; eni tí o máá n rúnra sá omo jé eni tí kìí fara bale.

field: n; (People were working in the field.) (All of them are experts in their chosen field.) igbé; pápá Àwon ènìyàn n sisé nínú pápá Isé tí a yàn láàyo. Gbogbo won ni ó dángajía nínú isé tí wón yàn láàyò

field: v; (Each of the main parlies fielded more than 300 candidates.) (The BBC had to field more than 300 phone calls after last night’s programme.) yan asojú Òkòòkan nínú àwon egbé òsèlú pàtàkí yàn ju òódúnrun olùdíje lo. Gba ìpè BBC ni táti gba ju òódúnrún ìpe lo, léyin ètò tí wón se lálé àná.

fierce: adj; (He suddenly looked fierce.) rpr`p; ,múná; gbóná ojú rè rorò lójijì.

fiery: adj; (They were bitten by a fiery serpent.) amúbíiná. Ejò amúbíiná ge won je.

fig: n; (The fig tree withered.)òpòtó Igi òpòtó náà ti w’’owé.

fight: v; (He fought with her.) jà; bá jà; jagun ó ba a jà.

fight: (He got into a fight with a man in the bar.) ìjà ó ní ìjà pèlú okùnrin tó wà nílé ìmutí náà.

figure: n; (There is falling in unemployment figuner.) (I was watching my figure.) nómbà to dúró fún nnkan Àwon nómbà tó duro fún àìrísese ti wa wile. àwòràn mo n wo àwòràn mi.

file: n; (Police have opened the file.) ìwe tí a n ko àwon iwé sí nínú Àwon olópàá ti sí iwé tí a n kó àwon ìwé sí nínú náà

file: v; (Please file it in my ‘Research’ file.) fi iwé pamó; to iwé pamo Jòwó fi pamo sínú ìwé tí mo n kó isé iwadìí mi sí nínú

fill:v; (Smoke filled the room.) kún Èéfún kún yàrá náà.

film: n; (My cousing is the film.) (She put a new film in her camera.) eré-oníse tí a gbà sínú fónrán aláwòrán. omodebìnrin tí ègbón mi obìnrin bí wa nínú ere-oníse tí won gba sínú fónran aláwòrán naa fónrán tó máa n wà nínú èro ayàwòrán ó fi fónrán túntun sínú èro ayàwòrán-an rè.

film: v; (They are fulming a new comedy.) yàwòrán eré-oníse; gbe eré-onise sínú fónrán aláwòrán Wón n gba eré-onisé apainlérìn-ín náà sínú fónrán aláwòrán.

filth: n; (The stench and filth of the prison is to much.) ègbin; èérí; òbùn òórùn burúku àti ègbìn ògbà èwòn náà pò ju.

filter: n; (I only smoke cigarettes with filter.) asé mo máa n mu sìgá pèlú asé nikan.

filter: v; (All drinking-water must be filtered.) sé; jò Gbogbo omi mímu lo ye kí a máa’sé.

filthy: adj; (The beggar dressed in filthy rays.)légbin; léèérí. Oníbárà náà wo àwon àkísà aso tó dòtí

fin:n; (He cut the tail fins of the fish.) (He touched the fin of the aeroplane.)lébè eja. O ge awon lébé ibi ìrù eja náà. Libi tí o dàsíi lebé eja lára okò bàálù ó fowo kan ibi tí o dábíi lébá eja lára okò bàálù náà.

final: adj; (He hasn’t read the final chepter of the book.) ti ìgbèyìn; ti ìparí ko tíì ka orí tó gbeyìn nínú ìwé náà.

finally: adj; (After a long delay the performance finally started.) nígbéyìn; ní ìparí Léyìn ìgbà tí a ti dúrói nígbèyin.

find: v; (Look what I have found.) (I managed to find solution to the problem.) rí wá Wo nnkan tí mo rí. Mo gbiyanju àti wa ojúùtú sí ìsoro náà.

fine: adj; (That is a fine performance.) (Sand is finer than gravel.) (The pencil has a fine point.) dára; dun Ìse/Imúse to dara niyan Kúnná Iyanrìn kúnná ju òkúta wéwèèwé lo. Tí ó rí tín-ín-rín Léèdì náà se enu tín-ín-rín.

fine: adv; dáadáa Ètò náà bá ni lára mu dáadáa.

fine: n; (Offenders will be liable to a heavy fine. owó ìtanràn; ìtanràn. Àwon òdaran yoo sán ìtànran to pò gidigidi.

finger: n; (He counted the guests on his finger.) ìka owó o ka iye àwon àlejò náà pèlú àwon ìka iye àwon rè.

finger: v; (He fingered the knife hidden in his pocket.) fi ìka kàn; fi ìka tó ó fi ìka kan obe tí ó wà ní ìpamó nínú àpo re.

fingerprint:n; (They took the fingerprint of the prisoner.) ìtèka wón gba ìtèka eléwòn náà.

finish: v; (He finished his work.) parí; tán o parí isée rè.

finish: n; (The story was a lie from start to finish.) ìparí; òpin Iró ni ìtan náà láti ìbèrè dé òpin. (He fired a hayatick.) (The engine isn’t firing. Yí ero dáadáa.Ero náà ko yí dáádáa.

fire: n; (Are you afraid of fire.) iná N je  o bèrù iná. 

fire: v; (He fired a pistol in to the air.) yìn, ta o yin ìbon iléwo sí aféfé. Tiná bò; finá sí; sin O tína bo koríko.

firearm: n; (He was accuused of firiarms offences.) ìbon .Wón fi àwon esùn pe ó n kó ìbon kiri kan an.

firefly: n; (He killed a firefly.) kokoro tannátanná kan o pa kòkòrò tánnátanná ken.

firelight: n; (Their shadows are dancing in the firelight.) ìtànsán má òjìjí won n jó nínú ìtànsán ína náà.

fireman: n; (The man is a fireman.) panápaná panápaná ni okùnrin náà.

firewood: n; ( He went to gather firewood.) igi ìdáná o lo wa igi ìdáná.

firm: adj; (We have no firm evidence.) le; lágbára; dúró sinsin. A kò ní èrí tó le.

firm: n; (I am the first in my family to go.) Ilé-isé o n ilé-isé àwón olùsirò owó (He has a firm of accountants.) Emi ni àkokó to lo sí ilé-iwé gíga nínú ebí mi. to university.

first: adj; (She won first price in the competetion.) àkókó; ekinní ó gba èbùn akókó nínú ìdíje náà.

first: adj; (Susan came into the room first.) kóko; sáájú Susan lo koko dé yàrá naa .

first:n; àkókó

fish:n; (He ate fish.) eja o je eja.

fish: v; (I often fish.) peja mo maa n peja dáadáa.

fisherman: n; (The man is a fisherman.) pejapeja; apeja pejapeja mi okùnrin náà.

fishery: n; (He is working in the ministry of Agriculture, fisheries and food.) eja pípa ó n sisé ní Ile-Isé ògbùn, Eja pípa àti ounje.

fishing: n; (Fishing is their main work in the Area.) eja pípa Eja pípa ni isé won gan ní agbegbe náà.

fishmonger: n; ( I bought the fish from the fishmonger.) eléja-àwon tó n ta eja níle ìtàjà kékèèké mo ra eja naa lódè eléja.

fishnet:n; (He left his fishnet in the river.) àwòn ó gbàgbé àwon rè sódò.

fist: n; (He punched me with his fist.) èsè; ìkúùkù ó kaàn mi ni èsé.

fit: adj; (The food was not good for human consumption.) bá mu; tó oúnje náà kò ye fún jíje eniyan.

fit: v; (These shoes don’t fit me.) ye; bá mu Awon bàtà yii ko bá mi mu

fit: n; (The coat was a good fit.) ibámu Ewù náà ní ìbámu dáadáa

fix: v; (He fisced the shelf to the wall.) (Has the date of the next meeting been fixed.) 50 mo; fi bò ó so pákó tí a n kó nnkan sí náà mó ìgànná. Dá iye/ojo/ìgbà/akoko. N jé wón to dá ojó ìpàde tí o n bò.

flag: n; (White flag is a symbol of peace) (The bank of the river is full of flage.) àsiá; opagun Àsiá funfun túmò sí àlááfia. Irufe/òdòdó etí òdò kan Bèbè òdò náà kún fun koriko/òdòdò etí odo.

flag: v; (The streels were flagged to celebrate the team’s victory.) (My strength is flagging.) so àsiá wón so asía won sí gbogbo àwon ònà náà lati sàjoyò igbá oróke tí awon egbe agbábóòlu náà gbé.Lo síle; dínkù Agbára mi ti n dúnkù.

flame: n; (The flames were growing hugher and higher.) owó má owó má náà n pòn sí.

flame: v; (The logs were flamed on thd earth.) jó pèlú owó má owóiná jó àwon ìtì igi náà sóri ilè.

flamingo: n; (The hunter killed a flamingo.) eye ako ode náà pa eye àkò kan

flam: n; (Have some more flan.) àkàrè eléyin nínú Gbo àkàrà eléyin nínú síí.

flank: n; (She patted the horse’s flank) egbé nnkan; ìnà ó fi owo gbá esin náa ní ègb é.

flank: v; (She left the courtroom flanked by armed quard.) dúró tì légbèé ó kúró nínú ìyàrá ilé ejó náà pèlú awon olùso meji légbèe re.

Oju-iwe Keji[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

flannel: n; (He bought a flannel shirt.) aso tí owúu rè kún ná ó ra èwù tí a fi aso tí òwúu rè kúnná se.

flap: n; (With a flap of its wings’the bird was gone.) (The flap of the envelope is cut off.) ìgbònyé pìpì pèlú ìgbònyé pìpì, eye náà lo iwé pelebe tàbí paálí pelebe tàbí páànù pelebe tí a so mo nnkan láti maá fí dé e. Enu apò iwé náa ti já.

flap:v; gbònyé. Eye náà gbònyée rè o sì fò lo The bird flapped its wings and flew away.

flare: v; (The match flared and went out.) jó bùlàbùlà. Ìsáná náà jó bùlàbùlà o si kú.

flare: n; (The flare of the match lip up his face.) iná bùlàbùlà. Iná bùlàbùlà ìsáná náà fi oju rè han.

flared: adj: (He wore a flared trousers.) tí ó fe nísàlè ó wo sokoto tó fè nísàle.

flash: n: (flashes of light were followed by an explosion.) mònàmóná Ariwo(ará) ló máà n telé mònàmóná.

flash: v; (The lightning flashed in the distance.) ko mònà; ko sàn-àn. Imólè náà ko mònà láti òókan wá.

flask: n; (The woman bought a flask.) ságo kekere obìnrin náà ra ságó kéreré kan.

flat: adj; pelebe ó fún mi ni pákó pelebe.(He gave me a flat wood.)

flat: n; (He beaterd the door with the flat of his hand.) (The man buit a flat.) ibi pelebe O fi ibi pelebe owó rè gbá ilèkùn náà. Ilé ìgbàlódé- irúfé ilé ìgbàlódé ti a ti kó ilé ìwe àti ilé –ìyàbgé pò mó àwon ìyèwù okùnrin náà kó ilé ìgbàlódé kan.

flatten: (The exercises will flatten your stomach.) té beere; se pelebe. Idárayá náà yóò so ikùn rè di pelebe.

flavour: n; (The food his sweet flavour.) òórùn dídùn ounje náà ni oorùn dídùn.

flavoured: adj; (He chrank flavoured yogunt.) tí ó lóòórun. Ó mu wàrà olóòórùn.

flax: n; (a flax in his vineyard.) ògbò ó gbin

flea: n; (The dog has fleas.) ìdun; eégbon. Ajá náà ní eégbon.

flee:v; (He burst into tears and fled.) sá; lo ó bú sékún ó sì sá lo.

fleece: n; (The man sat on a fleece.) irin àgùntàn- awon àgùntàn tí a sí pèlú irun. Okùnrin náà jókòó lórí irun agùntan.

fleece: (The retailer fleeced the man.) ré je. Aláròbò náà ré okùnrin náà je

fleet: n; (There is a reduction in the size og British fleet.) egbé okò; òwó okò Egbé oko àwon Gèésì ti n dín kù.

fleet: adj; (The Child is very fleet.) yara; jáfáfá ní ìrìn. omo náà yara dáadáa.

flesh: (The trap had cut deeply into the robbit’s flesh.) eran are pàkúté náà ti ge eran are ehoro náà wonú.

flex: (He stood on the side of the pool flexing his muscles.) ró; lò ó dúró légbèé odò náà, o n ró ara rè.

flick: v; (The horse was flicking flies away from his tail.) gbón. Esin náà n gbon awon esinsin kúrò ni irù rè.

flicker: v; (The light flickered and went away.) jó bàìbàì Iná náà jó bàìbàì o sí kú

flicker: n; (The flicker of the candle has gone out.) jíjó bàìbàì iná Jíjó bàìbàì opá ìmólè na’`a ti kú. flight: n; (He had a comfortable flight.) (We are booked on the same flight.) (Bird is easily recognized in flight.) (There was a flight of refugees from the advancing foreces.) ìrìn àjò lójú òfuurufú ó rìn ìrìn-àjò tí o rò ó lórùn lójú òfuujrufá Okò ìfuurú tí ó n lo nínú irùj;e ìrìn-àjò okò ojú òfuurufú kan náà ní a jo sán owó fún Ìfò tàbí fófò Fírò ni a fi máa n dá eye mò pèlú ìròrùn. Ìsákúrò nínú ewu. Awon àtìpó náà ni ìsákúrò ni agbegbe àwon ológun tí n bò lódò won

flimsy: adj; (He made a flimsy table.) féléfélé; tí kò lágbára.Ó se tábìlì féléfélé tí ko lágbara.

fling: v; (She fling the letter sown on the table.) so; jù ó so léta náà sílè lórii tábàlì

fling; n; (We had a brief fling, but it is over now.) àsìkò ìgbádùn kúkúru A ní àsìkò ìgbádùn kúkúru, èyí tí ó ti kaja báyìí.

flint: n; (His eyes were as hard as flint.) òkúta ìbon: irúfé òkúta kan tí ó máa n sána tí ó bá so nnkan Ojú rè le bní òkúta ìbon.

flit: v; (The buterfly flitted from flower to flower.) fò kiri labalábá náà fò kiru láto orí òdòdò kan sí òmíràn.

float: v; léfòó. Àpò oníke náà léfòó lójú omi A plastic bag was floatry in the water.

flock: n; (He has a flock of cattle.) agbo eran; òwó eran ó ní agbo àgùntan.

flock: v; (Huge numbers of birs had flocked together by the lake.) kóra jo pò òpòlopo àwon eye ti kóra won jo pò sí etí àdágún náà.

flood: n; (The heavy rain has caused floods in many parts of the country.) ìkún omi òkò nlà náà ti dá àwon ìkún omi sílè ni òpòlòpò àwon agbègbè ni orílè-èdè.

flood: v; (If the pipe bursts it could flood the whole house.) kún pèlú omi Tí opá omi náà bá bé ó lè kún gbogbo ilé pèlún omi.

floor: n; (His body was hying on the kitchen floor.) ilè ilé Ara rè wà lórí ilè-ilé ìdáná náà. flop: (Exhausted, he flopped down into a Chair.) subú lulè ó subu lulè sìnú àgà nígbà tí ó rè e.

flour: (He bought a bag of flour.) ìyefun ó ra àpò ìyèfun kan.

flour: v; (Roll the dough on a lighthy floured surface.) fi ìyèfun yí fi ìyèfun yí àkàrà náà fééréfé.

flourish: v; (The plarnts folourish in a damp climate.) rúwé ; gbilè, Àwon irúigbìn náà n gbilè lásìko Ogìnnìnntin.

flow:v; (Blood flowed from the cut on her head. sàn èjè n sàn jáde lójú ogbé tó wà lóro rè.

flow: ìsàn (She tried to stop the flow of blood from the wound.) ó gbiyanju láti da ìsàn èjè tí ó n jáde lójú ogbé náà dúró.

flower: n; (The plant has a beautiful brightred flower.) òdòdó. Irúgbìn náà ni òdòdó tó dáa tí ó pupa tí o n tàn.

flower: v; (This particular variety flower in July.) yo òdòdó. Irúfé àwon wònyí máa n yo òdòdó nínú osu Agemo (osù keje).

flower.pot. (He bought a flower pot.) ìkòkò òdòdó ó ra ìkòkò òdòdó kan.

fluent: adj; (She is fluent in polish.) lè sòrò jojo ó lè sòrò dáadáa lede pólìísì.

fluid: n; (The doctor told him to drind plenty of fluids.) nnkan sísàn onísegun náà ní kí o máa mu òpò nnkan sísàn.

fluke: n; (They ar determine to show that their last win was no fluke.) oriire àìrotélè; orí-bándé W;on pínnu láti fi han pe bíbórí won tí ó gbèyìn kìí se oríbandé.

flute: n; (I have a flite.) fèrè mo ní fere kan.

flutter: v; (The butterfly fluttered from flower to flower.) fò níbàábalè Labalábá náà fo níbàánbalè lati orí òdòdó kan sí omiran.

fly:v; (A wasp had flown in through the windon.) fò Agbón ti fò wole láti ojú ferese.

foal: n; (He has a foal.) omo esin; omo kétékétè ó ni omo esin kan.

foam: n; (He slept on a foam mattress.) tìmùtìmù; ìfoòfó ó sun lórí tìmùtìmù.

foam:v; (The tooth paste foamed in his mouth.) ru ose ìfoyin náà ru ní enu rè.

focus: n; (It was the main focua of attention of the meeting.) ìdojúko òhun lo jé ìdojuko ìpàdé náà gan-an.

focus: v; (I quickly focused the camera on the Children.) doju ko; wò mo yára doju ero ayàwòrán náà ko àwon omo náà.

fodder: n; (This plart is used a cettle fodder.) ohun ògbìn yìí ní wón n lò gégé bìí ounje àwon màálu.

foe: n; ota N kò bèrù otá kankan.(I fear no foe.)

fog: n; (We get heavy fogs on this cost in winter.) ìkuukùu A máa n ri ìkuukùu púpò òkun yìí ni àsìkò èèrùn.

fog: v; (The government was tryin to fog.) dàrú Ìjoba náà n gbìyànjú láti da ojú òrò rú kí o tó dìgbà ìbò náà. the real issues before the election.

fole: v; (He folded the map up and put it in his pocket.) ká ó ká àwòran ìtóka ìlú náà ó sì fi sí apo rè

fold: n; (He called on them to return to the fold.) agbo ó pè won kí won padà sínú agbo náà.

foliage: n; (foliage is very good for the livestocks.) (We folk, what are we going to do today?) ewé Ewé dára fun àwon eran òsìn ní jíje. àwon ènìyàn; mùtúmùtú’. Àwa mùtúmùtú, kí la ó se lónìí?.

force: n; (The rioters were taken away by force.) ipá; agbára Wón kó àwon tí ó n fa wàhálà náà lo pèlú ipa. force: v; (The president was forced into resign.) kàn nípá fún; fi ipá se wón kàn an nípà fún náà láti kòwé fi ipò re sílè.

fool: n; (Don’t be such a fool!) òmùgò Ma ya omùgò báyen!

fool: v; (I fooled him into thinking that I was giving him some money.) tàn; mú ní èegò Mo tàn an láti máa rò pe mo n fún un ní àwon owó kan.

foolish: adj; (I was folish enough to believe what jeff told me.) go Mo gò tóbéè láti gba ohun ti Jeff so fún mi gbé.

for: prep; (There is a letter for you.) fun léta kan wà fín o.

forbid: v; (My doctor forbid me sugar.) dá lékun; kà léèwò onísègùn mi da mi lékun súgà jíje.

ford: v; (The were fording the river near the village.) koja lórí omi/wà kojá lórí omi wón n koja lori omi lébàá abúlé náà.

foreign: adj; (You could tell was foreign by the way she dreesd.) ti ilú mìíràn Nípa bí ó se woso o lè so fún un pé omo ilú nìíràn ni

foresee: v; (We do not foresee any problem.) wòye. A kò wòye pé wáhale kankan yóò wà.

forest: n; (He lives in the fores.) igbó egbán Inú igbó ló n gbe.

forever: adv; laelae; títí táé N ó máa rántí ojó ayò náa láéláé

forge: v; (He forged a spear for my father.) (He was sent to prison for forging important papers.) ro ó ro òkò fún bàbáà mi. Se ìdàrò Wón rán an lo sí èwòn nítorí pé Ó se ìdàrò àwon iwé pàtàlà náà.

forge: n; (The golds mith was in the forge.)

aró; àgbède Alágbede náà wà nínú ebu. 

forgery: n; (This passport is a forgery!) ìdàrò Ìdàrò ni fóntò pélébé yìí!

forget: v; (I forget who told me about this book.) gbagbe mo gbàgbé eni to so nipa ìwé yìí fún mi.

forgive: v; (I forgave him for being rude to me.) dáríjin. Mo daríjì fún pé ó se ìpánle sí mi.

forgiveness: n; (It is good to show forgiveness to people who are sorry for doing wrong.) idaríji ó dára kí a máa fi ìdáriji hàn fún àwon tó bá káàánú fún sise asìse.

fork: n; (We can eat rice with a fork.) (Take the right fork.) amuga A lè fi amuga ìjeun je ìresì. Ibi ònà ti pín sí mèjì Gba èyí ti ó lo sí apá òtún níbi tí ònà ti pin sí méjì náà.

fork: v; (The road forks son after the bridge.) (fork left after lthe bridge.) pín sí méjì kò jìnnà sí afara náà ti ònà náà fí pín sí méjì. ya sápá kan ya sí apá osì léyìn afárá náà

form: n; (He is form 2 now.)  (The rock was in the form of a cow lying down.) (If you fill in this form, you can take books out of the library.) ìjókòó ó wà ní ìjókòó kejì bayìí Ìwò; àwòràn Òkùta náà dàbí àwòrán tó dùbúle. Irúré ìwé kan tí a lè. Tí o bá ko nnkan sí inú àwon àlàfo tó wá nínú ìwé títè yìí, o lè mu àwon iwé jade ni yàrá ìkówèé pamósí.

form: v; (A table is formed of a flat piece of wood.) (We formed a club for people whe liked cars.) se; mo sèdá pákó pelebe ni a fi n se tábìlì. A sèdá egbé fún àwon ènìyàn to féràn okò ayókélé

formal: adj; (If you vist important people, you must wear formal dress and behave in a formal way.) (There are Rose and Agnes; the former is wearing a green dress, the latter is wearing a white one.) (The owner of this shop lis obolu the former owner was Mrs Àjàlá.) bí ìse; bí àsà; tí ó tònà Tí a bá lo kí àwon ènìyàn pàtàkì a gbódò aso to bá àsà mu a sì gbódò hùwa bí o ti tònà. Ti àkókó Rose àti Agnes ló wà, ení àkókó wo aso aláwò ewé; eni ìgbèyin wo funfun. Tí ìgbà laelae ; ti télètélè. Eni tí o ni ilé ìtàjà yìí ni oboli eni tó ni télètélè ni arábìnrín Àjàtá.

formation: n; (The formation of rocks takes very many years.) ìsèdá; ìdásilè Ìsèda àwon okúta máa n gba òpòlopò odún.

fort: n; (The others dicided to go out for the day and left me holding the fort.) odi Awon ìyókù pínu láti jáde lo ní òsan wón sì fi mi sílè kí n dí odí mú.

fortify: v; (They fortified the building againt the attack of enemies.) (He fortified the wine with alcohol.) mo odi sí; se ààbò fún; Wón mo odi fún ilé náà nítorí ìjà àwon òtá. Fún ni okun; fún ní agbára. Ó fún wáìnì náà pèlú otí lílè.

fortnight: n; (In a fortnight’s time I will be in Lagos.) osè méjì Ní òsè méjì sí àsìkò yìí n ó wà ní ilé Èkó.

forture”n; (I wish you good fortune.) (He made a fortune by selling house.) oríire; alábàápàdé. Mo gbagura kí o se dábàápàdé nnkan rere. Orò; òpolopò owó. Ó ní òpòlopo owó nípa títa ilé.

fortunate: adj; sse oríire o se oríi re pe ó ní òpòlopò àwon ebí tó láàánú (You are fortunate to have so many kind relatives.)

fortunately: adv; (You have a headache? Well, fortunately I have some medicine with me.) pèlú oríire ó ní èfórí ? ó dáa o se oríire mo ní àwon òògùn kan pèlí mi

forward: adv; (When the lights were green the car moved forwards.) díwájú Nígbà tí àwon ína oko náà mú àwò ewé jáde, okò ayókélé náà ló siwájú.

foufou: n; (He ate foufou.) fùùfú- irúfé oúnje kan tí a fi gbájùúdá/ ègbé se ó je fùùfú.

fought: v; jà (He fought him.) ó bá a jà.

foul: adj: (There was a foul small coming from the rubber factory.) légbin; léèrí òórùn tó légbin n jade síta láti ilé-isé róbà náà.

found: v; (I found my book.) (The school was founded in 1954.) rí mo rí iwé mi. Dá sílè:Wón dá ilé-ìwé náà sílè ní osùn 1954 foundation: n; (The foundation of the school was in 1954.) ìdásílè Idásílé ilé-iwé náà waye ní odùn 1954. ìpìlè ilè : ìsolè. Abala ilé tí ó wá nínú ilè ní a n pè ní ìpìlè ilé.

founder: n; (The parts of a building under the ground are the foundation.) (He is the founder of the school.) olùdásílè óun ni olùdasile ilé-ìwé náà.

foundry: n; (He works in an iron foundary.) ilé-isé tí a ti n ro irín ó n se isé ní ilé-isé ìserin.

fountain: n; (In the hotes garden was a pretty fountain with water coming out of the mouth of a stone lion.) ìsun; orísun Nínú ogbe ilé ìtura náa ìsun kan tí ó rewà tí omi ti n tí jáde lénu kìnìún a fi òkúta gbé.

four: n; (Four and three are seven (4+3=7).) eérin Eérin àti eéta jé eéje

four: adj; (I have four brothers.) mérin mo ni arákùnrin merin.

fourteen: n; (Thirteen is followed by fourteen.) Eérìnlá Eérinla lo telé eetàlà.

fourteen: adj; (My father had fourteen brothers.) mérìnlá Baba mi ni arákùnrin mérìnlá.

fourty: adj; (There are forty boys running in the race.) ogójì ogójì omokùnrin lo n sáre nínú ìdiye náà.

fourty: n; (Ten and thints are fourty.) Eéwàá àti ogbòn jé ogójì.

fowl: n; (He has many fowls.) eye; adìye ó ní òpòlopò àwon àdìye.

fox: n; (The hunter killed a fox.) kòlòkòlò Ode náà pa kòlòkòlò kan

fraction: n; (Only a small fraction of my frends have a television.) ìpín; ìdá Enu(ìpìn) díè nínú àwon oré mi ló ni èro mohun-máwòran.

fracture: n; (He has a fracture in his leg.) sísé egungun ; rírò egungun Egungun ese rè ró.

fracture:v; (His leg was fractured in an accident.)se egungun; ró egungun Egungun esè rè sé nínú ìjàmbá mótò.

fragment: n; (There was a fragment of glas on the floor.) èérún Èérún ìgò iwà lórí ilè

frail: adj; (He is very frail after his long Illness.) láìlera; láìlágbara; aherepè ko ní agbára kankan mó léyin òpòlopo àárè náà.

frame: n; (These modern buildings have steel frames.) férémù Àwon ilé ìgbàlódé wònyí ni àwon férému tí a fi ayó se.

frame: v; (He framed the photograph of his girlgriend.) se ìlàpà nnkan ó se ìlàpa fóntò òrébìnrin rè.

framework: (The froamework of the hit is wood.) ìlàpo pákó ní wón fi se ìbìpo àgó náà.

fraud: n; (He was sent to prison for fraud.) (He said he was very rich, but he is a fraud –he is evern poorer than me!) ètan; èrù; ayédèrú Won rán an lo sí ogbà èwòn fùn èrú síse. Eni tí ó n sèrú; elétàn. Ó so fún ni pé òun lórò. Dáàdáà sùgbòn elétàn ni ó táláka ju èmi páàpáà lo!

free: adj; (You are free to go anywhere you want.) (He was given a free ticket for the football match.) (He is free with his money.) di òmìnìra; ní omìrira o ní òmìnra lati lo sí ibikíbí tí o bá fé. Ní ìsimi. Ó ní ìsimi ni aago méwàá, o lè ri nígbà yen lófèé wón fún un in ìwé ìwolé lófèé lati wo idíje bóòlù aláfesègbá náà.Lawó Ó lawó pèlú owó rè.

free: v; (He freed the birds from the cages.) fún ní ònìnìra; tú sílè yònda ó tú àwon eye náà sílè nínú àwon àgò náà.

freedom: n; (It is good to have the freedom to choose what job you do.) òmìnira o dára kí ènìyàn ní ònìnira lati yan isé tó wù ú láàyò.

freely: adv; (He gave him his money freely.) (You can speak freely.) lófèé ó fún un lówó lófèé. Láìni odiwon/wàhálà O lè sòrò pèlù ìròrùn. freeze: v; (The water froze and turned into ice.) dì omi náà dì sí yí padà sí yìnyín.

freezer: n; (We keep frozen food in a freezer.) èro amú-nnkan –tutù èro amú-nnkan-dì A máà n kò àwon ounje dídé sínú èro emú-nnkan-dì.

frequent: adj; (I enjoyed his frequents visits.) nígbà gbogbo; nígbàtùugbà Mo gbádun àbèwò ìgbàgbogbo rè.

freequently: adj; (She cooks chicken frequently; about three times a week.) lémólemó; nigbàgbogbo ó máa n se eran adìye lemolemo, ní bíi ìgbà méta nínú òsè kan.

fresh: adj; (These vegetables are fresh.) (Use a fresh page.) tútù Àwon èfó yìí tutu.Tuntun; àkòtun Lo`oju ewé tuntun.

friction: n; (A car’s tyre’s become hot becouse of the friction with the road surface.) ìlora ohun méjì Àwon táya okò ayókélé náà di gbígbóna nitorí tí wón n lo ojú ìná bí wón ti n yí.

friday: n; (He was here on last Friday.) ojó Etì. f wa níbí ní ojó Etì tó koja.

fridge: n; (There is some milk in the fridge.) èro amú-nnkan-tutù wàrà díè wà nínú ero amú-nnkàn tutu.

friend: n; (Agnes is simion’s girl friend.)òré Agnes jé orébìnrin símíónì

fright: n; (He gave her a fright.) èrù; ìròyà ó mu ìfòyà bà a.

frighten: v; (He was frightened of the frierce dog.) dérù bà ; dáyà fò. Ajá tó rorò náà dérù bá á.