Roza Otunbayeva

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Roza Otunbayeva
Роза Отунбаева
President of Kyrgyzstan
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
3 July 2010
AsíwájúKurmanbek Bakiyev
Prime Minister of Kyrgyzstan
Acting
In office
7 April 2010 – 19 May 2010
AsíwájúDaniar Usenov
Arọ́pòVacant
Minister of Foreign Affairs
In office
1992–1992
ÀàrẹAskar Akayev
Alákóso ÀgbàTursunbek Chyngyshev
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbíOṣù Kẹjọ 23, 1950 (1950-08-23) (ọmọ ọdún 73)
Osh, Soviet Union (now Kyrgyzstan)
Ẹgbẹ́ olóṣèlúSocial Democratic Party
Alma materLomonosov Moscow State University

Roza Isakovna Otunbayeva (Àdàkọ:Lang-ky, Rọ́síà: Роза Исаковна Отунбаева; ojoibi August 23, 1950) ni Aare orile-ede Kyrgyzstan. Won bura re ni July 3, 2010, leyin to ti dipo bi olori igbadie leyin ijidide April 2010 to fa lilekuro Aare Kurmanbek Bakiyev lori aga. Otunbayeva je alakoso oro okere tele ati olori ipade ileasofin fun Egbe Toseluaraalu Awujo ile Kyrgyzstan.

Otunbayeva ni obinrin akoko ti yio je Aare orile-ede omo egbe CIS/SCO.



Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]