Físíksì
Ìrísí
(Àtúnjúwe láti Ìmọ̀dánidá)
Físíksì (lati inu Ìmọ̀ aláàdánidá) tabi Fisiki (Physics) jẹ́ ìmọ̀ sáyẹ́nsì tí ó ń ṣe ìwádí èlò ati awon okun ti won n je sise akiyesi ninu àdánidá.
Awon onímọ̀ aláàdánidá n se iwadi isise ati awon ohun-ini eda aye to yi wa ka lati àwọn ẹ̀yà ara ti won n se gbogbo awon elo ti a mo (Ìmọ̀aláàdánidá ẹ̀yà ara, particle physics) titi de bi àgbàlá-ayé se n wuwa bi odidi kan (ìmọ̀ìràwọ̀títò astronomy, ìmọ̀ìdáyé cosmology).
Ise imo aladanida ni lati wa awon ofin ijinle ti gbogbo awon ohun aladanida n tele.
Ko si iye igbedanwo to le fi han pe iro mi je tito, sugbon igbedanwo kan pere le fihan wipe o je aito – Albert Einstein
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |