Aarun Ómi ati Àyipada Óju Ọjọ

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Àyipada Óju Ọjọ lo ti fa óriṣiriṣi itankalẹ ààrun ati ailèra papa èyi to farapẹ ti ómi. Ìpa Àyipada óju ọjọ lo ti wa kakiri àgbàye ninu ọgbẹlẹ, ikun ómi, ójó rirọ to lagbàrà ati ómi to lọwọrọ. Eyi lo fa aàrun omi to si tu bọ pọsi kakiri ààgbàyè. Àlèkun ótutu ati iyipada ninu ójó mu ki ààrun ómi jẹ ọkan gbogbi ninu ipa ètó ilèra to wa latara àyipada óju ọjọ[1][2][3][4].

Ààrun Ómi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ààrun ómi jẹ awọn aisan to wa lati ara koko ti àkolè fójuri to wa ninu ómi. Àmi aisan naa ni ìgbè gbùrù, ìba, àilera ati bibajẹ ẹdọ[5][6].

Àyipada óju ọjọ ti ko ipa ninu itankalẹ awọn kokoro aifojuri yi, ọkanlara awọn aisan naa ni àisan ìgbẹ gbùrù to wa latari mimu omi ti ko da tabi lilo wọn eyi lo si ti fa iku aimoyè awọn ọmọọdè[7][8][9]. Aisan ìgbẹgbùrù ti ṣè ókunfa iku awọn èniyan millionu 1.4-1.9 lagbàyè[10]. Gẹgẹbi ajọ ijọba to da lóri igbẹ̀jọ ti ayipada ójù ọjọ eyi ti ólóyinbo mọsi "Intergovernmental Panel on Climate Change (IPCC)", Àlèkun ti ba itankalẹ ààrun omi latara ayipada óju ọjọ[1][11].

Ìpa ti Àyipada Óju Ọjọ kó ninu Ààrun Ómi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Iwọn otutu ati óóru[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Iwọn ààlèkun óóru fa alèkun kokoro aifojuri ninu ara awọn èrankó ati ninu ómi mimu. Nigba óóru, omi mimu jẹ̀ àlèkun eyi lo maa fa itankalẹ awọn kokoro aifojuri ti oun fa ààrun ómi bi igbẹ gbùrù. Ni àgbègbè to gbóna papa èyi to ni ómi kèkèrè alèkun wa ninu ómi ti wọn gba ti wọn si tun ló pada. Eyi le fa alekùn ninu ómi ti o ti dọti[12][13].

Òjó ati Ikun Ómi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ayipada ójù ọjọ ti fa alekùn ba ójó rirọ eyi lo fa aimoye ikùn ómi. Iwadi sọpè ààrun igbẹ gbùrù ati ikun jẹ ọkan lara ipà ọjọ. Latara ójó to pọ lo fa alèkun ba kokoro aifójuri to si ko iparun ba imọtótó ati ómi àgbègbè naa[14][15].

Ikun ómi ko ipa lori ètó ilèra, kokoro aifojuri to wa lati igbọsẹ awọn eniyan tabi èrankó to wa ni inu ilẹ ko iparun ba ómi ilẹ to si maa nkóba awọn èniyan to ba mu iru ómi naa.Ójó to ba lagbara maa da ómi ódó pọ mọ omi to wa lati ṣalanga to si jẹ akoba fun omi mimu to wa lati ilẹ[16][17].

Ikun ómi jẹ ọkan lara ókunfa àlèkun to ba ààrun omi papa ni órilẹ ede to ti dagba sókè ni awọn àgbègbè ti akoba ti ba ómi mimù wọn[18].

Ọgbẹ̀lẹ[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ójó ni awọn àgbègbè kan lo ti fa ọgbẹlẹ̀ si agbègbè ti ójó ko rọ. Eyi lo fa èkun ba awọn idọti inu omi kiwọn kuró, eyi lo mu ki kokoro aifojuri dojukọ iwọn ba ómi to wa ni agbègbè naa[19][20].

Ọgbẹlẹ tun maa njẹ ki awọn èniyan gbẹkẹlè ómi ojo ati ómì èti ọna eyi lo maa fa akóba latara kokoro aifojuri to maa nfa ààrun ómi[21].

Awọn Itọkasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. 1.0 1.1 Levy, Karen; Smith, Shanon M.; Carlton, Elizabeth J. (2018-05-02). "Climate Change Impacts on Waterborne Diseases: Moving Toward Designing Interventions". Current Environmental Health Reports (Springer Science and Business Media LLC) 5 (2): 272–282. doi:10.1007/s40572-018-0199-7. ISSN 2196-5412. 
  2. Jung, Yong-Ju; Khant, Naing Aung; Kim, Heejung; Namkoong, Sim (2023-03-25). "Impact of Climate Change on Waterborne Diseases: Directions towards Sustainability". Water (MDPI AG) 15 (7): 1298. doi:10.3390/w15071298. ISSN 2073-4441. 
  3. Semenza, Jan C. (2020-04-20). "Cascading risks of waterborne diseases from climate change". Nature Immunology (Springer Science and Business Media LLC) 21 (5): 484–487. doi:10.1038/s41590-020-0631-7. ISSN 1529-2908. 
  4. Levy, Karen; Woster, Andrew P.; Goldstein, Rebecca S.; Carlton, Elizabeth J. (2016-04-25). "Untangling the Impacts of Climate Change on Waterborne Diseases: a Systematic Review of Relationships between Diarrheal Diseases and Temperature, Rainfall, Flooding, and Drought". Environmental Science & Technology (American Chemical Society (ACS)) 50 (10): 4905–4922. doi:10.1021/acs.est.5b06186. ISSN 0013-936X. 
  5. "Climate change and infectious diseases — What We Do — NCEZID". CDC. 2021-09-17. Retrieved 2023-09-24. 
  6. "Does climate change increase the spread of infectious disease?". nationalacademies.org. Retrieved 2023-09-24. 
  7. "How climate change affects waterborne diseases — News". Wellcome. 2022-05-12. Retrieved 2023-09-24. 
  8. Noureen, Afshan; Aziz, Rabia; Ismail, Abdullah; Trzcinski, Antoine P. (2022-04-01). "The Impact of Climate Change on Waterborne Diseases in Pakistan". Sustainability and Climate Change (Mary Ann Liebert Inc) 15 (2): 138–152. doi:10.1089/scc.2021.0070. ISSN 2692-2924. 
  9. "Diarrhoeal disease". who.int. 2017-05-02. Retrieved 2023-09-24. 
  10. Dattani, Saloni; Spooner, Fiona; Ritchie, Hannah; Roser, Max (2023-07-03). "Diarrheal Diseases". Our World in Data. https://ourworldindata.org/diarrheal-diseases. Retrieved 2023-09-24. 
  11. Nations, United (2023-01-18). "The Health Effects Of Global Warming: Developing Countries Are The Most Vulnerable". United Nations. Retrieved 2023-09-24. 
  12. "The Effect of Climate Change on Waterborne Diseases". Safe Drinking Water Foundation. 2017-01-04. Retrieved 2023-09-24. 
  13. Funari, Enzo; Manganelli, Maura; Sinisi, Luciana. "Impact of climate change on waterborne diseases". Annali dell'Istituto Superiore di Sanità (Editrice Kurtis srl) 48 (4): 473–487. doi:10.4415/ANN_12_04_13. ISSN 0. 
  14. "Climate change and waterborne and vector‐borne disease". academic.oup.com. Retrieved 2023-09-24. 
  15. Shafii, Nur Zahidah; Saudi, Ahmad Shakir Mohd; Pang, Jyh Chyang; Abu, Izuddin Fahmy; Sapawe, Norzahir; Kamarudin, Mohd Khairul Amri; Mohamad, Mohamad Haiqal Nizar (2023-06-02). "Association of Flood Risk Patterns with Waterborne Bacterial Diseases in Malaysia". Water (MDPI AG) 15 (11): 2121. doi:10.3390/w15112121. ISSN 2073-4441. 
  16. Udonquak, Aniefiok (2022-10-29). "Floods: Communities at risk of water borne diseases, malaria". Businessday NG. Retrieved 2023-09-24. 
  17. Okaka, Fredrick Okoth; Odhiambo, Beneah D. O. (2018-10-17). "Relationship between Flooding and Out Break of Infectious Diseasesin Kenya: A Review of the Literature". Journal of Environmental and Public Health (Hindawi Limited) 2018: 1–8. doi:10.1155/2018/5452938. ISSN 1687-9805. 
  18. Shayo, Godfrey Michael; Elimbinzi, Elianaso; Shao, Godlisten N.; Fabian, Christina (2023-07-24). "Severity of waterborne diseases in developing countries and the effectiveness of ceramic filters for improving water quality". Bulletin of the National Research Centre (Springer Science and Business Media LLC) 47 (1). doi:10.1186/s42269-023-01088-9. ISSN 2522-8307. 
  19. "Health Implications of Drought". CDC. 2018-12-07. Retrieved 2023-09-24. 
  20. "Droughts bring disease: here are 4 ways they do it". PreventionWeb. 2023-03-14. Retrieved 2023-09-24. 
  21. Tomarchio, Adrien (2017-03-27). "Battling effects of the drought: a victim of water-borne diseases speaks". ACTED. Retrieved 2023-09-24.