Abdullah Gül
Ìrísí
Abdullah Gül | |
---|---|
11th President of Turkey | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga 28 August 2007 | |
Alákóso Àgbà | Recep Tayyip Erdoğan |
Asíwájú | Ahmet Necdet Sezer |
Prime Minister of Turkey | |
In office 18 November 2002 – 14 March 2003 | |
Ààrẹ | Ahmet Necdet Sezer |
Asíwájú | Bülent Ecevit |
Arọ́pò | Recep Tayyip Erdoğan |
Minister of Foreign Affairs | |
In office 14 March 2003 – 28 August 2007 | |
Alákóso Àgbà | Recep Tayyip Erdoğan |
Asíwájú | Yaşar Yakış |
Arọ́pò | Ali Babacan |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 29 Oṣù Kẹ̀wá 1950 Kayseri, Turkey |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Hayrünnisa Gül |
Alma mater | Istanbul University University of Exeter |
Signature | Abdullah Gül |
Website | Tccb.gov.tr |
Abdullah Gül, GCB, GColIH, Ph.D. (ojoibi October 29, 1950) ni Aare ikokanla lowolowo orile-ede Turki lati 28 August 2007. Teletele o ti je Alakoso Agba ile Turki lati 2002 de 2003, o si tun je Alakoso Oro Okere ile Turki lati 2003 de 2007.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |