Adenike Akinsemolu

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Adenike Adebukola Akinsemolu je olukoni nipa ayika Naijiria ati onisowo awujo. [1] Adenike je olukoni ni yunifasiti Obafemi Awolowo (Ile-iwe koleji Adeyemi). O je gbajumo nipa asiwaju onimo lori eto ayika. [1] [2] [3]

Adenike je oludasile Green Campus Initiative, ti o n se agbero fun ayika, akoko iru re ni ogba ile-iwe giga ni Naijiria .

Ise[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Adenike sise ni Clinton Foundation ni |New York.

Awon Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. 1.0 1.1 Hawken, Melanie (2016-02-20). "The startup story of a social entrepreneur in Nigeria building a new generation of environmentally conscious student leaders". Lionesses of Africa Website. Retrieved 2018-10-13. 
  2. Abumere, Princess Irede (2016-06-01). "New Media Conference 2016: Digital influencers get together to discuss new media in Nigeria". Pulse.ng. Retrieved 2018-10-13. 
  3. "Leading Ladies Africa". Leading Ladies Africa. 2018-08-14. Retrieved 2018-10-13.