Akínsànyà Sunny Ajọ́sẹ̀
Ìrísí
Akínsànyà Sunny Ajọ́sẹ̀ | |
---|---|
Olórí ilé-iṣé ìjọba fún àwon òṣìṣé ní ìpínlẹ̀ Èkó | |
In office July 2004 – February 2006 | |
Gómìnà | Bọ́lá Tinúbú |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 10 Oṣù Kejì 1946 Badagry, Lagos State, Nigeria |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | All Progressives Congress |
Alma mater |
Akínsànyà Sunny Ajọ́sẹ̀ jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí a bí ní ọjọ́ kẹwàá, Oṣù kejì Ọdún 1946. Ó j̣́e olóṣ̀elú àti ògá-àgbà òṣìṣẹ́ ìjọba[1] Ó ti fìgbà kan jẹ́ olórí ilé-iṣé ìjọba fún àwon òṣìṣé ní ìpínlẹ̀ Èkó láti oṣù keje ọdún 2004 sí oṣù kejì ọdun 2006.[2]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Akinsuyi, Temidayo (2 September 2014). "Security agencies must shun partisanship during polls – Ajose". The Daily Independent. http://independentnig.com/2014/09/security-agencies-must-shun-partisanship-polls-ajose/. Retrieved 19 April 2016.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- ↑ Abatti, Tolani (3 March 2015). "New Lagos Head of Service twice lucky, All the perks of office revealed". Ecomium Magazine. http://encomium.ng/new-lagos-head-of-service-twice-lucky-all-the-perks-of-office-revealed/. Retrieved 19 April 2016.