Azubuike Okechukwu
Ìrísí
Azubuike Godson Okechukwu (bí ní Ọjọ́ kọnkàndínlógún Oṣù kẹ́rin Ọdún 1997) jẹ́ alágbàṣe agbábọ́ọ̀lù ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà tí ó gbá bọ́ọ̀lù fún ẹgbẹ́ Yeni Malatyaspor ti Turkey, gẹ́gẹ́ bí a gbá ipò àárín.
Ìrìnàjò iṣẹ́ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]A bíi ní ìlú Katsina, Okechukwu gbá bọ́ọ̀lù fún Bayelsa United àti Yeni Malatyaspor.[1][2]
Ìrìnàjò iṣẹ́ rẹ̀ ní ilú òkèèrè
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Okechukwu gbá bóòlù ní ìgbà àkọ́kọ́ fún Nigeria ní ọdún 2016,[1] a yàn fún ìpèsè eléni márùndínlógójì fún ọdún 2016 Summer Olympics.[3]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ 1.0 1.1 "Azubuike Okechukwu".
- ↑ Azubuike Okechukwu profile at Soccerway.
- ↑ Oluwashina Okeleji (24 June 2016).