Bimbo Akintola
Bím̀bọ́ Akintọ́lá | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | 5 Oṣù Kàrún 1970 Ibadan |
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Iléẹ̀kọ́ gíga | University of Ibadan (B.A) |
Iṣẹ́ | Actress |
Ìgbà iṣẹ́ | 1995–present |
Bímbọ́ Akíntọ́lá (tí wọ́n bí ní Ọjọ́ Kàrún-ún, oṣù karùn-ún ọdún 1970) jẹ́ òṣèrébìnrin sinimá àgbéléwò ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.[1][2][3][4]
Ìbèrè ìgbé ayé àti èkó rè
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Wón bí Akíntôlá ní ojó Karùn ún osù karùn-ún odún 1970 [5] bàbá rè jé omo bíbí ìpínlè Oyo tí ìyá rè sì jé omo bíbí Ìpínlẹ̀ Edo. Ó lo sí ilé-ìwé alákóbèrè ti àwon Ìjo Àgùdà tì ó wà ní ni agbègbè Maryland ní Ìpínlẹ̀ Èkó. Leyin eyi, o tesiwaju lo si ile eko girama ti awon ologun ti o wa ni ìpínle Èkó. O k'eko gboye imo nipa ere ori itage lati ile eko giga Yunifasiti ti Ibadan.[6][7]
Iṣẹ́
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ise akoko ti o gbe jade ni eyi ti o se ninu fiimu OWO BLOW ni odun 1995, eleyi ti oun ati Femi Adebayo jo se ati eyi ti o tun se leyin re ti a n pe ni Out of Bounds ni odun 1997[8] ti o se pelu Richard Mofe Damijo. Awon onworan fiimu so wipe oun ni o mo ere itage se ju ni odun 2013 nigba ti won wo ipa ti o ko ninu fiimu ni odun 2013 ninu eto ti a ti n mo riri awon elere ori itage ni orile ede Naijiria.
Àwọn Àṣàyàn Iṣẹ́
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Owo Blow (ọdún 1995)
- Out of Bounds (ọdún 1997)
- The Gardner (ọdún 1998)
- Dangerous Twins (ọdún 2004)
- Beyond the Verdict (ọdún 2007)
- Smoke and Mirrors (ọdún 2008)
- Hoodrush (ọdún 2012)
- AyÍtale (ọdún 2013)
- Heaven's Hell (ọdún 2015)
- 93 Days (ọdún 2016)
Àwon Ìtọ́ka sí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Bimbo Akintola, Toyin Oshinaike in troubled union". punchng.com. Archived from the original
|archive-url=
requires|url=
(help) on 14 August 2014. Text "http://www.punchng.com/entertainment/arts-life/bimbo-akintola-toyin-oshinaike-in-troubled-union/" ignored (help); - ↑ "Bím̀bọ́ Akintọ́lá, Falode canvass support for working mothers". punchng.com. Archived from the original on 14 August 2014. Retrieved 13 August 2014.
- ↑ "Age is no barrier to marriage – Bimbo Akintola". punchng.com. Archived from the original on 14 August 2014. Retrieved 13 August 2014.
- ↑ "Bimbo Akintola cries out: I don’t need a husband!". vanguardngr.com. Retrieved 13 August 2014.
- ↑ "30 Nigerian entertainers presently in the league of 40s". December 9, 2015. http://thenet.ng/2015/12/special-report-30-nigerian-entertainers-presently-in-the-league-of-40s/.
- ↑ "Bimbo Akintola Biography". gistus.com. Retrieved 13 August 2014.
- ↑ "Why I Am Not Yet Married At 42..Bimbo Akintola". cknnigeria.com. Retrieved 13 August 2014.
- ↑ "Out of Bounds". Internet Movie Database. Retrieved 25 October 2014.