Egbé Akómolédè

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Ẹgbẹ́ Akọ́mọlédè àti àṣà Yorùbá jẹ́ àgbárí-jọ-pọ Àwọn olùkọ́ nílé ìwé alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀, girama àti ilé ẹ̀kọ́ fásitì ti ìjọba pẹ̀lú aládàáni jákè jádò ilẹ̀ Nàjíríà. Ẹgbẹ́ yìí ń ṣojú Yorùbá níbi ìgbé lárugẹ èdè, àṣà àti ìdàgbà sókè ìṣèṣe Yorùbá [1][2][3]

Àwọn ìtọ́ka sí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Egbe Akomolede ati Asa Naijiria". Archived from the original on 27 August 2018. Retrieved 30 October 2018. 
  2. "Yoruba, a Must for All – Egbe Akomolede – Radio Nigeria Ibadan". Radio Nigeria Ibadan – Radio Nigeria Ibadan. Uplifting the people and uniting the Nation. (in Èdè Ruwanda). 2018-08-07. Retrieved 2018-11-01. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  3. admin (2018-07-26). "Latest news about Egbe Akomolede from Nigeria & world". TODAY.NG. Retrieved 2018-11-01.