Jump to content

Irène Joliot-Curie

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Irène Joliot-Curie
Ìbí(1897-09-12)12 Oṣù Kẹ̀sán 1897
Paris, France
Aláìsí17 March 1956(1956-03-17) (ọmọ ọdún 58)
Paris, France
Ọmọ orílẹ̀-èdèFrench
PápáChemistry
Ibi ẹ̀kọ́Sorbonne
Doctoral advisorPaul Langevin
Ó gbajúmọ̀ fúnTransmutation of elements
Àwọn ẹ̀bùn àyẹ́síNobel Prize for Chemistry (1935)

Irène Joliot-Curie (12 September 1897 – 17 March 1956) je onimo sayensi ara Fransi, ohun ni omobinrin Marie Skłodowska-Curie ati Pierre Curie ati iyawo Frédéric Joliot-Curie. Lokanna mo oko re, Joliot-Curie gba Ebun Nobel fun Kemistri ni 1935 fun iwari won iranna afowose. Eyi so ebi Curie di ebi to ni awon elebun Nobel julo titi doni.[1] Bakanna awon omo mejeji awon Joliot-Curies, Hélène ati Pierre na je onimo sayensi pataki.[2]


  1. "Nobel Laureates Facts: 'Family Nobel Laureates'". Nobel Foundation. 2008. Retrieved 2008-09-04. 
  2. Byers, Nina; Williams, Gary A. (2006). "Hélène Langevin-Joliot and Pierre Radvanyi". Out of the Shadows: Contributions of Twentieth-Century Women to Physics. Cambridge, UK: Cambridge University Press. ISBN 0521821975.