James Gandolfini
James Gandolfini | |
---|---|
Gandolfini in 2011 | |
Ọjọ́ìbí | James Joseph Gandolfini, Jr. Oṣù Kẹ̀sán 18, 1961 Westwood, New Jersey, U.S. |
Aláìsí | June 19, 2013 Rome, Italy | (ọmọ ọdún 51)
Orúkọ míràn | jósẹ́fù |
Iṣẹ́ | Olòséré |
Ìgbà iṣẹ́ | 1987–2013 |
Olólùfẹ́ | Marcy Wudarski (m. 1999–2002) Deborah Lin (m. 2008–2013, his death) |
Àwọn ọmọ | 2 |
Website | https://en.m.wikipedia.org/wiki/James_Gandolfini
Ọmọ ilé-ìwé = Rutgers Ifáfitì- New Brūnswik |
James Joseph Gandolfini, Jr. (ojoibi Oṣù Kẹ̀sán 18, 1961 – Kẹfà 19, 2013) je osere ara Amerika. Fún ipa rẹ̀ gẹ́gẹ́ bi "Toni Sọ̀pránò" Alága àwon Ńsọmí tó jé Itálíán-Amẹ́ríkàní nínú eré HBO tí wọ́n pè ní "Awọn Sọ̀pránósì".
Ogbẹ́ni Jákọ́bu Gàndólfínì jr. jẹ ẹ̀yẹ Emmy Mé̩ta, ẹ̀yẹ SAGA Márùn-ún, ẹ̀yẹ GGA ẹyọ kan. Ipa rẹ́ gẹ̀gẹ̀ bí "Toni Sọ̀pránò" tó̩ka si gẹ́gẹ́ bí Olósèré tí ó tóbi jù àti tó lọ́lá jùlọ nínú amóhùnmáwòrán wa.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Ògbẹ́ni Gàndólfínì pẹ̀lú gẹ́gẹ́ bi àgbàjọ ènìyàn ọ̀tún Virgil nínu eré True Romance (1993), lẹ́ftẹ́nántì Bọ́bì Douhertì nínu Krímsọ́n Tīde (1995), Kọ́nẹ́lì Wíńtà nínu The Lāst Kástù (2001), àti Alákoso ìlu Nēw Yọ̀rk nínu Thē Tákíng of Pẹ́lhàm 123 (2009). Awọn eré rẹ̀ míràn pẹ̀lú Gẹt Shọrti (1995), Whẹre the Wild Things Are (2009), Ẹnough Said (2013). Ọgbẹ́ni Gāndolfini gba ẹ̀yẹ Skreen Aktors Guild Award àti yíyàn Boston Sosiety of Film Kritiks Award fún olósèré tí ó sé àtìlẹyìn lẹ́yìn iku rẹ̀. Ní ọdún 2007, Ogbẹ́ni Gāndolfini
Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]https://en.m.wikipedia.org/wiki/James_Gandolfini
Wikimedia Commons ní àwọn amóunmáwòrán bíbátan mọ́: James Gandolfini |