Oluwarotimi Odunayo Akeredolu
Ọlọ́lájùlọ Oluwarotimi Odunayo Akeredolu | |
---|---|
Gómìnà Ìpínlẹ Ondo | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga ọjọ́ kẹfàdínlọ́gbọn oṣù kejì ọdún 2017 | |
Asíwájú | Olusegun Mimiko |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | Oluwarotimi Odunayo Akeredolu 21 Oṣù Keje 1956 Owo, Ìpínlẹ Ondo |
Ọmọorílẹ̀-èdè | Orílẹ̀ edè Nàijíríà |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | All Progressives Congress |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Betty Anyanwu-Akeredolu |
Alma mater | Obafemi Awolowo University |
Occupation | Olóṣèlú agbẹjọ́rò |
Website | aketi.org |
Oluwarotimi Odunayo Akeredolu, SAN, or Rotimi Akeredolu, (ọjọ́ ìbí 21 July 1956 - 27 December 2023) jẹ́ olóṣèlú àti agbẹjọ́rò ará Nigeria tó jẹ́ Gómìnà Ìpínlẹ Ondo ní orílẹ̀ edè Nàijíríà lọ́wọ́lọ́wọ̣́. [1] Akeredolu tún jẹ́ ìkan nínú àwọn agbẹjọ́rò àgbà ti ilẹ̀ Nàìjíríà (SAN) tí ó sì jẹ́ ààrẹ ẹgbẹ́ amòfin ti orílẹ̀ edè Nàijíríà ní ọdún 2008.[2]
Ìbímọ Rẹ̀ Àti Ẹ̀kọ́ Rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Wọ́n bí Akeredolu ní ọjọ́ kọ̀kàn-lé-lógún oṣù keje ọdún 1956 ní Owo sí Reverend J. Ola Akeredolu ti ẹbí Akeredolu àti Lady Evangelist Grace B. Akeredolu ti ẹbí Aderoyiju ti Igbotu, Ese Odo, ní Ìpínlẹ̀ Ondo.
Akeredolu ṣe ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ìkẹ́kọ̀ọ́ rẹ̀ ní ilé-ìwé ìjọba kan ní Ọ̀wọ̀. Ó tẹ̀síwájú láti lọ sí Aquinas College, níAkure, Loyola College ní Ìbàdàn àti Ilé-ẹ̀kọ́ gíga kan ní Ayetoro, fún ẹ̀kọ́ ilé-ìwé gíga rẹ̀ àti ẹ̀kọ́ ilé-ìwé gíga gíga rẹ̀. [3] Orúkọ àárín rẹ̀ "Ọdúnayọ̀" túmọ̀ sí "Year of happiness" ní èdè Gẹ̀ẹ́sì. [4] Ó lọ sí Ilé-ẹ̀kọ́ gíga ti Ifẹ̀ (tí a mọ̀ sí Obafemi Awolowo University) láti kọ́ ẹ̀kọ́ òfin, tí ó sì ṣe ayẹyẹ ìparí ẹ̀kọ́ rẹ̀ ní ọdún 1977.[5] Wọ́n pè é sí Nigerian Bar ní ọdún 1978.[6][7]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Breaking Ondo decides Inec officially declares Rotimi Akeredolu Governor elect". www.premiumtimesng.com. Retrieved 27 November 2016.
- ↑ "Nigerian Bar". www.nigerianbar.org. Archived from the original on 8 October 2011. Retrieved 27 November 2016.
- ↑ "LOYOLAN EMERGES NBA PRESIDENT". Loyola College Ibadan Old Boy's Association. Archived from the original on 11 December 2010. Retrieved 13 February 2010. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Odunayo". Online Nigeria: Nigerian Names and meanings. Archived from the original on 20 December 2014. Retrieved November 20, 2014. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "NBA Under Me Won't Fail Nigerians – Akeredolu". Nigerian Bar Association. 4 September 2008. Archived from the original on 27 July 2011. Retrieved 13 February 2010. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedself
- ↑ "Oluwarotimi Odunayo Akeredolu Biography and Detailed Profile". Politicians Data (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-05-22. Archived from the original on 23 June 2020. Retrieved 2020-05-30. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help)