Rosie Stephenson-Goodknight
Ìrísí
Rosie Stephenson-Goodknight | |
---|---|
Àwòrán Stephenson-Goodknight tí Wikimedia Foundation yà ní gbangba ní ọdún 2015 | |
Ibùgbé | Ìlú Nevada ní ìpínlẹ̀ California[1] |
Orúkọ míràn | Rosiestep |
Iṣẹ́ | alámójútó okùnòwò |
Gbajúmọ̀ fún | olótú Wikipedia |
Àwọn ọmọ | Sean |
Àwọn olùbátan | David Albala (bàbá bàbá rẹ̀) Paulina Lebl-Albala (ìyá ìyá rẹ̀) |
Awards | Èbùn kóríyá Wikipedia (2016) |
Rosie Stephenson-Goodknight, tí a tún mọ̀ sí Rosiestep ní Wikipedia jẹ́ olótú Wikipedia ọmọ ìlú Amẹ́ríkà tí ó gbìyànjú láti ri wípé ojú opó ìmọ̀ ọ̀fẹ́ yìí jẹ́ oun tí takọ tabo á má a dásí tí ó sì ṣe àgbékalẹ̀ ọ̀pọ̀lọpọ̀ ètò tí ó jẹ́ ki iye àwọn àyọkà nípa obìrín tó póṣùwọn pọ̀ síi. [2] Ó ti kọ ọ̀pọ̀lọ́pọ̀ àyọkà tí ó sì gba ẹ̀bún kóríyá Wikipedia ti ọdún 2016.
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Liu, Teresa Yinmeng (July 3, 2016). "Nevada City's Rosie Stephenson-Goodknight named co-Wikipedian of 2016 for addressing online gender gap". Western Nevada County Union. Archived from the original on August 26, 2016. https://web.archive.org/web/20160826085139/http://www.theunion.com/news/localnews/22749884-113/nevada-citys-rosie-stephenson-goodknight-named-co-wikipedian-of-2016. Retrieved July 6, 2016.
- ↑ "Wikipedia editing marathons add women's voices to online resource". Houston Chronicle. http://www.houstonchronicle.com/life/article/Adding-women-s-voices-to-Wikipedia-12344424.php.