Jump to content

Teresa Teng

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Teresa Teng
Teng in 1979
Orúkọ àbísọ鄧麗君
Ọjọ́ìbíTeng Li-yun (鄧麗筠)
(1953-01-29)29 Oṣù Kínní 1953
Baozhong, Yunlin, Taiwan
Aláìsí8 May 1995(1995-05-08) (ọmọ ọdún 42)
Chiang Mai, Thailand
Burial placeChin Pao San, New Taipei City, Taiwan
25°15′04″N 121°36′14″E / 25.251°N 121.604°E / 25.251; 121.604
Iṣẹ́
  • Singer
  • actress
  • television personality
  • philanthropist
  • lyricist
Ìgbà iṣẹ́1966–1995
Alábàálòpọ̀Paul Quilery (1989–1995)
Musical career
Wọ́n tún mọ̀ọ́ bíi
  • Deng Lijun
  • Tang Lai Kwan
  • Teng Li Chun
Irú orin
Labels

Teng Li-chun (Chinese: 鄧麗君; pinyin: Dèng Lìjūn; (Oṣù kìíní ọjọ́ kọkàndínlọ́gbọ̀n, ọdún 1953 - Oṣù karùn-ún ọjọ́ kẹjọ, ọdún 1995), tí a mọ̀ sí Teresa Teng, jẹ́ olórin, òṣèré, olórin àti olùrànlọ́wọ́ ará Taiwan. Àwọn kan ń pè é ní "Ọbabìnrin Ayérayé ti Àsìá Pop", a kà á sí ọ̀kan lára àwọn olórin Àsìá tó ṣe àṣeyọrí jùlọ tí ó sì ní ipa jùlọ ní gbogbo ìgbà.[1] [2]

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. Hernández, Javier C. (2019-01-21). "In the Heart of Beijing, a Taiwanese Pop Idol Makes Fans Swoon". The New York Times. Retrieved 2024-11-07. 
  2. Schweig, M. (2022). Renegade Rhymes: Rap Music, Narrative, and Knowledge in Taiwan. Chicago Studies in Ethnomusicology. University of Chicago Press. p. 58. ISBN 978-0-226-82058-3. https://books.google.com.ng/books?id=v6p5EAAAQBAJ&pg=PA58. Retrieved 2024-11-07.