Jump to content

Tristan Thompson

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Tristan Thompson
Thompson with the Cavaliers in 2019
No. 13 – Cleveland Cavaliers
PositionCentre / Power forward
LeagueNBA
Personal information
Born13 Oṣù Kẹta 1991 (1991-03-13) (ọmọ ọdún 33)
Toronto, Ontario
NationalityCanadian
Listed height6 ft 9 in (2.06 m)
Listed weight238 lb (108 kg)
Career information
High schoolFindlay Prep (Henderson, Nevada)
CollegeTexas (2010–2011)
NBA draft2011 / Round: 1 / Pick: 4k overall
Selected by the Cleveland Cavaliers
Pro playing career2011–present
Career history
2011–presentCleveland Cavaliers
Career highlights and awards
Stats at NBA.com

Tristan Trevor James Thompson (ojo ibi, Ojo Ketala, Osu Keta, odun i991)  je omo bibi ilu Canada ti o n ere idaraya ti boolu alafowogba-sinu-awon fun awon Cleveland Cavaliers ti National Basketball Association (NBA). O gba ere idaraya yi fun saa kan ni ile iwe giga Texas ki a to gba wo'le si owo kerin ti gbogboogbo awon Cavaliers ni odun 2011 NBA draft . [1] Awon egbe yi ni o tun s'oju fun ilu Canada ni ibi idije gbogboogbo ti orile ede naa. Thompson wa lara awon ti o bori nibi idije NBA championship pelu awon Cavaliers ini odun 2016.

  1. "Tristan Thompson". NBADraft.net. Retrieved 2012-11-06.