Wizkid
Ìrísí
(Àtúnjúwe láti Wizkid (musician))
WizKid | |
---|---|
Wizkid níbití ó ti nṣe ìfilọ́lẹ̀ àwo-orin ní ọdún 2013. | |
Background information | |
Orúkọ àbísọ | Ayodeji Ibrahim Balogun |
Ọjọ́ìbí | 16 Oṣù Keje 1990 Lagos, Lagos State, Nigeria |
Irú orin | |
Occupation(s) |
|
Years active | 2001-present |
Labels | Starboy |
Associated acts |
Ayodeji Ibrahim Balogun , a bi i ni ojo kerindinlogun osu jeje odun 1990, oruko itage e ni Wizkid, o je̩ olukọrin ti owa lati ilu Naijiria. Lati ọmọ ọdun mọkanla ni oti bẹrẹ sini kọrin, otun ṣe record pẹlu awọn ọmọ ẹgbẹ Glorious Five, ti ohun ati awọn ọrẹ rẹ dasilẹ. Ni ọdun 2009, Ogbeni Banky W gba wizkid si inu ẹgbẹ akọrin rẹ, eyi tin jẹ Empire Mates Entertainment (E.M.E). Ni ọdun 2010 , wizkid di gbajumọ aye pẹlu orin rẹ Holla at Your Boy lati ẹrọ orin rẹ Superstart ojade ni 2011.Ẹrọ orin ẹkeji ti wizkid gbejade ni ọdun 2014 ni awọn orin bi "Show You the Money" ,Jaiye Jaiye ati bẹbẹlọ[1][2]
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Muziek voor iedereen.". Muziek voor iedereen - Spotify (in Èdè Dọ́ọ̀ṣì). Retrieved 2020-04-25.
- ↑ "Wizkid Archives". Pan African Music. Retrieved 2020-04-25.