Jump to content

Èdè iṣẹ́ọba

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Èdè isẹ́ọba)
Ètò òfin èdè ìṣèjọba Europe.

Èdè isẹ́ọba orílẹ̀-èdè kan jẹ́ èdè tí wọ́n fún ní ipò pàtàkì ní irúfẹ́ orílẹ̀-èdè náà.