Ọbẹ̀ banga

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Ọbẹ̀ Banga)
Ẹ̀bà àti ọbẹ̀ banga

Ọbẹ̀ Banga jẹ́ ọbẹ̀ kan tí wọń maá n pèlò látara èkùrọ́ táa fí n pèsè epo pupa. Ó wọ́pọ̀ láàrin àwọn ìran Urhobo ti ìpínlẹ̀ Dẹ́ltà lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà, ó sì gbajúmọ̀ káàkiri àwọn orílè-èdè mìíràn ní ilè adúláwọ̀. Ìran Akan ti orílẹ̀-èdè Ghánà mòó sí "Abenkwan."