Jump to content

Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ Abaji

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Abaji)
Ilé-iṣẹ́ omi Nestle yìí wà ní Àbajì, ní olú-l̀lú orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. A fún un ní àṣẹ ní ọdún 2016. Ó jẹ́ ikẹrin irurẹ tí ilé iṣẹ́ yi ní ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.

Agbegbe Ijoba Ibile Abaji wa ni Abuja, Nigeria.