Adéníyì Johnson

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Adéníyì Johnson tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kẹtàdínlógbọ̀n oṣù kejì ọdún 1978 (27th February 1978) jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèré sinimá àgbéléwò ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Ó ti ju ogún ọdún lọ tí ó ti ń ṣeré tíátà, ṣùgbọ́n ìràwọ̀ rẹ̀ bẹ̀rẹ̀ sí ní tàn nígbà tí ó kópa nínú eré orí tẹlifíṣàn kan tí àkọ́lé "Tinsel". Gbajúmọ̀ òṣèrébìnrin, Tóyìn Àìmàkhù ni ìyàwó àkọ́fẹ̀ Adéníyì Johnson, ṣùgbọ́n kò pẹ́ tí ìgbéyàwó wọn foríṣánpọ́n.[1][2] [3]

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Ikande, Mary (2017-12-09). "Exploring private life and career of popular Nollywood actor and Tinsel star Adeniyi Johnson". Legit.ng - Nigeria news. Retrieved 2020-01-01. 
  2. "Adeniyi Johnson begs ex-wife Toyin Abraham to sign divorce papers". Premium Times Nigeria. 2018-12-05. Retrieved 2020-01-01. 
  3. Published (2015-12-15). "Toyin refused to sign our divorce papers, estranged husband, Adeniyi Johnson laments". Punch Newspapers. Retrieved 2020-01-01.