Jump to content

Akòpe

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Akope)
Akọ̀pẹ ń gun Igi-ọpẹ.


Isé ọ̀pẹ-kíkọ jé ọ̀kan lára àwọn isé ìbílẹ̀ ilè Yorùbá. Nínú Isé yìí bákan náà ni a ti máa n gba ògùrò tàbí ẹmu.