Jump to content

Atúmọ̀-Èdè (Gẹ̀ẹ́sì-Yorùbá): D

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Atumo-Ede (English-Yoruba): D)

[[Atumo-Ede (Yoruba-English): [ ETAN]

dab: v; (She stopped crying and dabbed her eyes.) jèjé; nù fééréfé ó dáké ekùn, o sì nu ojú rè nù.

dab: n; (She gave her daughter a dab on her face after greeting her.) ìlù jéjé; ìfowokán feerefe, ifowó-nù fééréfé o fún omo re ni ifowonu fééréfe lorí léyùn to kìí tán.

daft: n; (Don’t be so daft.) aláìní-làákàyè; alání-òye. Má yan aláàlóye.

dainty: adj; (She is a dainty Child.) dídùn; dára; elegé omo tó rewà ni.

daisy: n; (The garden is fill of daisy.) irúfé koríko kan tó ó máa n ní òdòdó fúnfun lórí pèlú pupa résúrésú láàrin rè. Imí ogba náà fún koríko tí Ó ní òdòdò funfun lórí pèlú anu pupa láàrin rè.

dale: n; (The dale is very deep.) ògbun ògbun náà jùn.

dangerous: adj; (The river is highly dangerous for the swimmers.) lèwu odò náà léwu gidegidi fún àwon òmùwè.

darling: n; (She is my darling.) olùfé olùfé mi ni.

darling: adj; (My darling daughter is here.) olólùfé olólùfé omo mí obìnrin wà nibi.

dart:n; (He killed the bird with dart.) òkò o fi oko pa eye náà.

dart: v; (The mouse darted away when I approached.) lo kíákíá; sáré lo lojiji. Eku ilé náà sáré lo lójiji nígbà tí mo sún mó on.

dash: v; (I must dash.) sún sìwájú kíákíá, lo kíákíá mo gbòdò máà lo kíakíá.

dash: n; (Try to make a dash of freedom.) ìsúnsíwáhú mura láti ni ìsúnsíwájú òmìnira. Ami kan ti a n fi sí ìwé kíko. 

date: n; (What is today’s date?) déètì kí ni déètì.

date: v; (Don’t forget to date your cheque.) fi déètì ojó sínu ìwé kíko ma se gbagba láti fi déètì sínú sòwédówó re.

daughter:n; (The man has three daughters.) omobìnrin okùnrin náà ní omonùnrin méta.

dawn: n; (We must start at dawn.) àfèmójú. A gbódò bèrè nì àfèmójú

dawn: v; (Day was dawning as we left.) yé;bers sí ni mole ojúmó ti mo bí a se kúrò.

day:n; (He has been working all day.) ojú òsán ó ti n sisé ní gbogbo ojú òsán

daylight: n; (He stole the car in the daylight.) ojúmomo ojúmomo ló jí okò ayókélé nàá.

daytime: n; (You hardly see owls in the daytime.) ojú òsán; òsán gangan o kò lè sábà rí àwon eye òwìwí ni òsán gangan.

dead: adj; (The tiger fell dead.) di òkú; láìlémìí. Ekùn náà subú lulè ó dòkú.

dead: n; òkú. (We carried the wounded and the dead off the battle field.) A gbé awon to fara pa ati awon okú náà kúrò lójú ìjà.

dead: adv; (You are dead right!) pátápátá ó gbà a pátápátá

deaf: adj: (She was born completely deaf.) tí ó dití. A bii ládití pátápata.

deaf:n; (They are all deafs.) eni tí ó dití. Adìti ni gbogbo won

deal: n; (The workers are hoping for a better pay deal.) ìpín ; àjọsopò. Àwon òsìsè náa n retí ìpín/ isé tí yoo mú owó to gbe péélí wa.

deal: v; (He dealt me four cards.) pín ó pín páálì ìkonkan-sí méin fún mí.

dear: adj; (My daughter is very dear to me.) tí ó sòwón omobìnrin ni sòwón sí ni púpò.

dear: n; (Come here, my dear.) Èdá gìdi; ẹni rere, olùfẹ́ máa bò níbi, olùfé mi.

death: n; (Her death was a shock to him.) ikú ikú re bá a lójijì.

debate:n; (After much debate we decided to leave the place.) àríyànjiyàn iléyin òpòlopò aríyànjiyàn a pinu láti kúrò nìbè.

debate: v; (What are you debating about?) se n se àríyànjiyàn kí le n se àríyànjuyàn lé lórí.

debit: n; (How much is my debit?) gbèsè. Eló ni gbese mi?.

debtor: n; (The man is my debtor.) onígbèsè onígbèsè mi lokùnrin náà.

decade: n; (It now a decade I saw him last.) odún mẹ́wàá ó pe odún mẹ́wàá tí mo rí i gbèyìn.

decay: v; (Sugar will decay your teeth.) rà bàjé súgà yóò ba eyín re jé.

decay: n; (That system slowly fell into decay.) ìbàjẹ́; rírá; aláìsìsé díédíè.	

deceive: v; (He deceived him.) tàn jẹ ó tàn an jẹ.

deceiver: n; (The man is a deceiver.) elètàn elètàn ni okùnrin náà.

december: n; (He was born in December.) Ọ̀pẹ̀; Oṣù kejìlá ọdún. A bíi nínú Oṣù Ọ̀pẹ̀.

decent: adj; (The lady is decent.)finju. Omoódan náà fúnju.

decide: v; (I have decided to go.) pinnu. Mo ti pinnu láto lo.

decidous: adj; (He went to hunt in a decidours forest.) tí n wówé lódoodún ó lo sode nínú igbó tí o n wówé lódoodún.

decimal: n; (I don’t understand decimal fraction.) tí o ní se pèlú èwá. Ìsirò orí pípín sí méwàá kò yé ni dáadáa.

deck: n; (My bad is on the top deck.) pákó tí a fit è okò. Erù mí wà lórí pákó tí afi lé okò lókè.

declaration: n; (The was a declaration of wan yesterday.) ikede ìkéde ogún wáyé lánàá.

declare: v; (He declared that the war is over.) kéde; tenumó ó kéde pé ogún ti tan.

decorate: v; (The table was decorated.) se lósòó wón se tábìlì náà lósòó.

decline: n; (There is a decline in the population of this country.) ìdínkù; iwásílè. Idúnke/ìwásílè wà nínú ìye olùgbé orìkè-èdè yìí. decline: v; (The influence declined after she lost the election.) dínkù; wá sílè. Gbajúmò rè dúnkù léyìn tí kò wolé ìbò.

deed: n; (You shall be rewanded according to your good deeds.) ìde;. A ó san èsan ìsé rere rè fún o.

deep: adj; (The well is very deep.) jìn; jinlè kàngs náà jìn dáadáa.

deer: n; (The hunter killed a deer.) àgbòrin, ìgalà, egbin ode náa pa àgbònrin.

defeat: v; (Thou shall defeat your enemies.) bì subu; borí. Ìwo yóò bóri àwon òtá re.

defeat: n; (Your enemies shall suffer defeat.) ìsubu. Àwon òtá re yóò rí ìsubú.

defend: v; (I will defend him.) gbèjà; dáàbò bp; se odi fun. N ó dáàbò bò o.

defense: n; (God is my defense.) ààbò; asà olórun in ààbò mi.

defenceless :n; (He is a defenceless Child.) aláìní-ààbò. Aláìláàbo omo mi.

deficiency: n; (Vitamin deficiency can lead to Illness.) ààpé. Àìpé oúnjẹ asaralóore lè fa àìsàn.

deficient: adj: (The Child is deficient in knowledge.) jé àìpé omo náàjé àìpé ogbón

define: v; (The powers of a judge are defined by haw.) túmò; so àsoyé òfin lo so àsoyé lóri agbára adájó.

definite: adj; (I have no definite plans for tomorrow.) (It is now definite that she’s going to be promoted.) pàtó. N ko ni àwọn àlàkale kankan pàtó fún òla. dájú ó di dájú báyìí pé won yóò gbé e ga.

defy: v; (She defied her parents and got married.) fojú ká mó; pè níjà; témbélú ó fojú témbélú àwon òbi rè ó sì lo lókò. degree: n; (She shows a high degree of skill in her work.) ìwon; ioò; oyè ó fi ìwòn làákaye gíga han nínú isé rè.

delay: n; (He did the work without any delay.) ìdádúró ó se isé láìsí ìdádúró kankan.

delay: v; (He delayed me for two hours.) dá dúró ó dá mi duro fun wakati meji.

delegate: n; (He sent his delegate to me yesterday.)ikò; asojú ó ran àwon ikò rè simi lánàá.

delegate: v; (The manager was delegated to reorganize the department.) yan asoju; yan ikò wón yan olùdarí náà láti tún èka náà tò.

deliberate: adj; (Deliberate sins have no forgiveness.) àmòómòse. Àwon èsè àmòómòda ko ní Ìdárijun.

deliberate: v; (He deliberated on my question before she answered me.) rónú ó ronú lórí ìbéèrè mi kó tó dá mi lóhùn.

delicate:adj; (That crate of egg is delicate to carry.) elegé pákó tí a to eyin sí yen se elegé láti gbé.

delicious: adj: (She prepared a delicious meal.) tí o ní àdídùn ó se oúnjẹ aládìídùn.

delight: n; (He takes delight in proving others wrong.) inú dídùn ó ní inú dídùn sí ìyàn jíjà.

delight: v; (He delights in shocking people.) ninu dídùn; dumú ó máa n nínú dídùn sí pipa àwon èniyàn lára.

deliver: v; (The woman just delivered a baby.) (She delivered the gods for me.) Gbà sile, bimo, obìnrin náà sese bimo ni. O gba ojà naa sílè fún mi.

delta: n; (I have been to the Niger Delta.) ibi tí odo tí peka sí wéewé sínú omi òkun. Mo ti de ibi ti odo oya ti pèka. 

deluge: n ; (The deluge destroyed many properties.) ìkún omi. Ìkún omi náà ba òpòlopò dúkìá jé.

demand: v; (He demanded for money.) bèèrè fún nnkan ó bèèrè fún owó.

demand: n; (The demand for the goods is too high.) ìbéèrè. Ìbéèrè fún òjá náà ga jù.

democracy: n; (Democracy is the best type of government.) èro ìjoba tolórí telémù. Ètò ìjoba tolorí telémù ló dára ju

demolish:v; (He demolished the shop.) (He demolished the statute) run ó run ilé ìtàjà náà. Bàjé, O ba òwò náà jẹ̀

demonstrate: v; (He demonstrated his loyality.) fi hàn, ó fi ìwa otító rè hàn

demonstration: n; (They gave a clear demonstration of their intentions.) ìfihàn, wón se afihàn èrò ọkàn rẹ̀ gbangba.

den: n; (He threw him into a lion’s den) ihò, ó so ó sínú ihò kìnìún.

dense: adj; (The forest is very dense.) dí, Igbo náà dí púpọ̀

dentist: n; (My brother is a dentist.) onísègùn eyín onísègùn eyín ni ègbón mi.

deny: v; (Peter denied jesus.) sẹ̀; kọ̀ fún, pétérù sẹ́ Jésù

depart: v; (He departed from him immediately) lo kúrò ;o lo kúrò lódò rẹ̀ lógán.

department: n; (He is the head of our department) èka ounní olorí èka tiiwa.

depend: v; (You cannot depent on his arriving on time.) gbókànlé; gbáralé, gbíyèlé. o ko lè gbára lé díde rè lákòókò.

dependant: n; (The Child is a dependant to his brother.) eni tí wón n gbó bùkátà rè.̣ Egbón omo náà ni ó n gbó bùkátà rẹ depict: v; (His novel depicts life of a Christian.) fihàn; se àpeere. Iwe ìtan arose rẹ se afihàn ayé onígbàgbó.

deposit: n ; (The shop promised to keep the goods for me if I paid a deposit.) ohun ìdógò; ilélè; ìjásílè Ilé itajà náà selérí láti pa ojà náà mo fún mi tí n ba le fi owo dógò sílè.

deposit: v; (The bus deposited them at the bustop.) dogol san àsansílè owo; dà sílè fi lélè. Okò náà dà wón sílè ni ibùdókò náà

depot: n; (He went to coca-cola depot.)  ilé ìsura; ibì ìpamó ó lo sí lbi tí wón n pa otí elérìndodo mó sí. 

depress: v; (Wet weather alwas depresses me.) rè sílè; mú káàánú òrìnrin n rè mi ní okàn sìlè.

depression: n; (He committed suicide during a fit of depression.) ìrèsílè; ìrèwèsì, ó bínú pa ara rẹ̀ nínú tí ìrèwèsì ọkàn.

depth: n; (The dept of the well is ten feet.) ìjinlè; jíjìn, jíjìn kanga náà jẹ́ ẹsẹ méwàá.

deputy: n; (I am acting as deputy till the manager returns.) asojú eni; àdèlé, mo n se gégé bí adelé títí tí aláse náà yóò padà.

descend: v; (The lift began to descend.) sọ̀ kale. Èro agbeni náà bèrè sí ní sòkàle.

describe: v; (He described his house.)júwe; fi òrò sàpeere ó júwe ilé rè.

desert: n; (Somalia is mostly desert.) asalè. Asálè ni gbogbo ile sòmàlíà ferè é jẹ́.

desert: v ; (He deserted his wife and Child.) kò sílè ó ko aya àti àwon omo rè sílè.

design: n; (Good designs will earn you more money.) àpeere; apèjúwe; àwòrán. Àwọn àwòrán dáadáa yóò mú owó wa fún o dáadáa sii.

design: v; (The route is designed to improve the flow of traffic.) (He designed the house.) sètò, wón sètò ònà náà dún ìgbòkègbòdò oko tó já gaara. se lósòó ó se ilé náà ní òsó.

desire: n ; (They had little desire for wealth.) ìfẹ́, ìwù. Ifé kékéré ni wón ni sí ọrọ̀

desire: v; (We desire happiness and health.) fé. A fé inú dídùn àti àlàáfía. 	 

desk: n; (He was writing on his desk.) tábìlì ìkòwé ó n kòwé lórí tábìlì ìkòwé rẹ̀.

despair: n ; (He gave up struggle in despair.) àìnírètí ó síwó ìlàkàkà pèlú àìnírètí.

despair: v; (Don’t despair! We will think of a way out.) so ìrèrí nú má so ìrètí nù, a o wá ònà àbáyo.


dispatch: v; rán lo. (American warships love been dispatched to the area.) (Àwọn Amẹ́ríkà rán àwọn okò ogun wọn lo sí agbègbè náà.

dispatch: n; (Government welcome the depatch of the peace keeping force.) ikò. Ijoba kí awon ikì tí wón rán sí lbi ìpètù-síjà náà kàábò.

desperate: adj; (The prisoners grew increasable desperate.) láìnírètí; gbékú ta fi àáké kórí. Àwọn ẹlẹ́wọn náà gbékú ta.

despise: v; (Don’t despise others.) kégàn; gàn; sáátá, mo sẹ gan elòmíràn.

despite: prep; (They had a wonderful holiday despite a bad weather.) bí ó tile jé pé, Wón gbádùn ìsùnin won bí ó tile jé pé ojú ojó kò dára.

destination: n; (He reached his destination safely.) òpin nnkan: lbi tí a n lọ, o dé lbi tí o n lọ láyò.

destine: v; (He is destined to be rich.) pinnu; kádàrá; yàn fún, ó kadara lati lówó.

destiny: n; (Destiny drew us together.) kádàrá, kádàrá lo fẹ̀ wá móra.

destroy: v; (He destroyed the bus) parun, run, ó pa okò náà run.

destruction: n; (Government inported weapons of mass destruction.) ìparun. Ijoba ra ohun ìjà ìparun wolé.

detail: n; èkúnréré ó kò láti so ní èkúnréré gan-an bí a ti se le yí òkun náà padà

detail: v; (The man details all the goods in his shop.) se lékùn-ún-réré okùnrin náà sètò ojà náà lékùn-ún-réré sí ilé ìtajà rè.

detain: v; (He was detained for 3 days.)

dá dúró; tì mole. Wón tì í mólé fún ojó méta.

detect: v; (Do I detect a note of wrong in your voice?) wá rí i. N jẹ́ mo se àwárí ègó nínú òrò rẹ?

detergent: n; (He washed his clothes with detergent.) ose lúbúlúbú, ó fi ose lùbúlúbúfo asọ rẹ̀

deteriorate: v; (His health deteriorate rapidly and he died.) rèyìn, bajé síí burú síí. Aláafíà rè n buru síi ó sì kú.

determine: v; (He determined to go.) pinnu; fowó sòyà ó pinnu láti lo. detest: v; (He detests stealing.) kóòríra, ó kóòríra olè.

devolop: v; (They sugar industry is developing.) dàgbà; gbòòrò; gbèrú. Ile isé suga náà n gbérú síi.

device: n; (Beware of the device of enemies.) ete; ogbón sora fún ete àwon òtá.

devil: n; (Devil is a liar.) Sàtánì, Bìlísì; ènìyàn buburú òpùró ni Sàtánì.

devote: v; (He devoted his time for communual work.) yà sótò; yà sí mímó ó ya àsìkò rè sótò fún isé ilú.

dew: n; (There was dew on the leaves.) ìrì; eeni. Irì wà lórí àwon ewé náà. diagonal: n; (He stood at the diagonal of the room.) lbi tó so igun méjì pọ̀ ó duro síbi tó so igun yàrá náà pọ̀.

diagram: n; (He draw the diagram with chalk.) àwòran, ó ya àwòran pèlú efun.

dial:n; (The dial of the clock has spoilt.) ojú aago ójú aago náà ti bàjé.

dial: v; (He dialled to my telephone number and called me.)  yí nómbá ero ìbánisoro lónà jíjùn làti peni básòrò o yí nómba ero ìbánisoro mi o si pè mi. 

diamater: n; (The diameter of the ball is not more than a feet.) ìlà tí ó gba àárín obíríkítí kója; fífè òbíríkítí fífè bóòlù náà ko ju ese bàtà kan lọ.

diamond: n; (He saw a diamond on his farmland.) òkúta oníyebíye jùlo ó rí òkúta oníyebíye jùlo lórí ilè oko rè.

diarrhoes:n; àrunsu; ìgbé òrìn. Ìgbé òrìn n dàá láàmu. (He is suffering from diarrhoea.)

diary: n; (He left his diary on the table.) ìwé ohun tí a se lójoojumò ó gbàgbé ìwé tí o n ko ohun tó se lójoojumó só ri tábìli.

dice: n; (He lost the dice.) àwon omo ayo tí o máa n ní igun mérin, ó so awon omo ayo onígun mérin nù.

dictate:v; (She dictates for her husband.) pase; so; pè fún láti ko ó máa n pase fún oko rè.

dictation: n; (The dictation is very simple.) àpeko. Àpàko náa ró dáadáa

dictator: n; (Our president is a dictator.) apàse eni tí o lágbára láti se ìlé bí ó ti wù ú. Àare wa máa n se ìlé bó ti wù ú.

dictionary: n; (He bought an english dictionary.) ìwé àsàjo òrò tí ó n so ìtumò òrò. Ó ra ìwé atúmo òrò ní ede Gèésì.

did: v; (He did the work.) se, ó se isé náà.

die: v; (He died yesterday.) ku, ó kú lánáà.

die: n; (He lost a die.) omo ayò onígun mérun ó so omo ayò onígun mérun kan nu.

diesel: n; (He filled his vehicle wigh diesel.) epo okò ó ra epo kún okò rè.

diet: n; (Illnesses are caused by poor diet.) oúnjẹ, oúnjẹ burúku ló n fa orísìírisìí àìsàn.

diet: n; (You ought diet and got exercise.) jeun ó ue kí o jeun kí o sì maa se idáraya.

differ: v; (Tastes differ.) yàtò ohun tí eni kòòkan fé yàtò síra

difference: n; (The difference is clear.) ìyàtò. Ìyàto náà hàn gbángba.

different: adj; (The tastes are different to mine.) yàtò. Ifé wón yàtò sí tèmi.

dificult: v; (She finds it difficult to stop smoking.) sòro ó sòro fún un láti síwóo sìgá mínu.

difficulty:n; (Bad planing will lead to difficulty later.) ìsoro; ìyonu; ìnira. Ète búburú yóò yorí sí ìsoro nígbèyìn.

dig: v; (I spent the morining digging.) gbélè; walè mo fi gbogbo owúrò gbélè.

digest: v; (Some foods take longer to digest.) dà (oúnje); tò léseese. Awọn óunjẹ kan máà n pé kí wọn tó dà.

digger: n; (He bought a new digger.) ìgbélè ó ra ìgbélè tuntun.

digit: n; (There are 3digits in “345’) nombà Nómba méta ló wà nínú “345’

dignify: v; (The ceremony was dignifed by the presence of the ambassador.) bu olá kún; bu iyi kún wíwá asojú ilè òkèèrè náà buyì kún ayeye náà.

dignitary: n; (The ara all dignitaries.) olóyè; olólá; eni iy. Eni iyì ni gbogbo won.

dignity:n; (He has a very great dignity.) olá ìyìn; igbéga ó ní ìyìn tó pò

dim: adj; (His eye sight is getting dim.) sújú; se bàìbàì; pòkúùdu ojú re ti n se bàìbàì.

dim: v; (Old age hasn’t dimmed her memory.) so dí bàìbàì; Arúgbó ko tíi so iyè rè dí bàìbàì.

dimension: n; (What are the dumensions of the room?) títóbí; ìbú àti òòró kí ni ìbú àti òòró iyàrá nàá.

duminish:v; (His strenght has diminished over the years.) dínkù; fà séyìn. Agbára rè ti dínkù láti odún yìí wá.

dim: n; (They are making so much dim that I can’t hear you.) ariwo nlá wón n paríwo nla débi pé n kò le gbó o.

dine: v; (We dinned together.) jéun. A jeun pò.

dinner:n; (He didn’t take his dinner yesterday.) oúnje alé kò je ounje alé rè lánáà.

dip: v; (Dip your pen into the ink.) fi bò, fi kálámù re bo tàdáwà.

dip: n; (We went for a dip.) ìwè nínú odò; ìrìbo inú omi.	A lo wè nínú odò. 

diploma: n; (He has a diploma in management.) ìwé tí àwon aláse fowó sí pé eni tí a fún ti gba oyè nílé ekó gíga. Ó ni ìwé àse ìgboyè nínú ìsàkóso ilé-isé.

diplomacy: n; (He solved the problem with diplomacy.) (International problems must be solved by diplomacy, not war.) ogbón èwè, ogbón ìsèlú; ó fí ogbón èwé yanjí ìsoro náà. Àjosoyépò láàrin àwon orílè-èdè. A gbódò máa yanjú wàhálà láàrin àwon orílè-èdè pèlú àjosoyépò, kìí se pèlú ogun jíja. diplomat: n; (The diplomats of the two countries have arrived.) asojú orílè-èdè ilè òkèerè. Àwon asojú orílè-èdè méjèjèèjì ti de.

direct: v; ( He directed me to you.) fí ònà hàn; se amònà; tóka sí júwe; darí ó darí mi sí o.

direct: adj; (He followed the direct route.) gán-àn; tààrà; pàtó ó gba ònà tàarà.

direction: n; (Has the wind changed direction?) ònà; tító àpeere; àpèjúwe se atégùn ti yí ònà ibi tí o n fé sí pàdà?

dirt: n; (His clothes were covered with dirt.) èérí; ègbin; erè; ìgbònsè. Èérí bo àwon aso rè.

dirty: adj; (He is too dirty.) dòtí; léèérí; légbin, lóbùn ó ti lóbùn ju.

disable: v; (He was disable after a car accident.) di aláìlágbára; di abirùn o di aláìlagbára léyìn ìjàmbá móto náà.

disabled: adj; (He is a disabled Child.) abirùn; aláìlágbára. Abirùn omo ni.

disadvantage: n ; (The plan has many disadvantages.) òfò; ìpalára. Ète náà ni òpòlopì ìpalára.

disagree: v; (He disagreed with him.) kò; se aláìré; yapa ó kò fún un.

disagreement: n; (There is disagreement between them.) àìgbóraeniyé ìyapa Aigbóraeniyé/ìyapa wà láàrin wọn.

disappear: v; (The plane disappeared behind a clould.) fara sin; kúrò lójú. Bàálù náà fara sin séyìn ìkùku.

disappoint: v; (The man disappointe me.) dá lára; ye àdéhùn okùnrin náà ye adéhùn pèlú mi.

disappointment: n; (Not getting the job was a bitter disappointment.) ìmófo; ìdálára; ìrètí tàbí ìgbékèlé tó sákìí. Àìrí isé náà gbà jé ìdálára tó koro. disaster: n; (His death was a great disaster.) ìjàmbá; àjálù. Ìjàmbá nla ni ikú rè.

disc: n; (He wears an identity disc round his nect.) ojú oòrùn; oju ohun tó té ohun tó rí pelebe ó wo ìdánimò pelebe yí orùn rè ká

dusciple: n; (Jesus had twelve disciples.) omo èyin omo èyìn méjìla in Jesu ní.

disciphinary: adj; (The formed disciphnary committee.) tí ó je mó ibiwí wón yan ìgbìmo abaniwí.

discipline: n; (Strict discipline is imposed on army recruits.) ìkóra-eni-ní ìjánu; ìbawí. Wón fún àwon omo ológun tí wón gbà ní ìbáwí tó lè.

discipline:v; (Parents should discipline their Childer.) bá wí. Àwon òbó gbódò máa bá àwon omo won wí.

discomfort: n; (He was in discomfort for 3 days.) ìror; inira ó wà nínú ìnira fún ojò métà.

discomfort: v; (Nothing has ever discomforted him in his life.) ni lára; fún ni ìrora kò sí ohun tó ní lára rí.

disconnect: v; (We have been disconnected.) yo kúrò; pìn níyà wón ti yo wá kúrò.

discount: n; (He was given discount on the goods he bought.) ìyokúrò; ìdín owó kù wón dín-in lówó kù lóri ojà tó rà.

discount: v; (He discount what the Child said.) sàìkà sí; dinwó kù ó sàaka ohun tí omo náà so sí.

discourage: v; (He discouraged the Child.) mú ìrèwèsí bá ó mú ìrèwèsì bá omo náà.

discover: v; (She was very delighted to discover a good restaurant nearby.) se àwárí; jágbón. Inú rè dùn láti se àwárí ilé ìjeun dáadáa ni itòsí.

discovery: n; (The researchers have recently made some important new discoveries.) àwárí; ìjágbón. Awon oníwadìí náà se àwon àwárí tuntun láìpé yìí. discriminate: v; (The law discriminated between.) fi ìyàtò sí; sàmì sí ofún fi ìyàto hàn láàrin ìmòòmò pàyàn àti àìmóòmò pàyàn. intentional and accidental killing.

discrimination: (He detests racial discrimination.) ìfìyàtò sí; ìsàmì sí. Ó korira eléyàmèyà.

discuss: v; (I refused to discuss the matter any further.) wádìí; so kínníkínní; mo ko láti sòrò náà kínníkínní siwájú síi.

discussion: n; (The matter will be dealt with in open discussion.) ìfòràwérò; àsogbè òrò; ìwadìí. A ó yanjú òrò náà nínu ìfòròwérò gbángba.

disease: n; (He preverted the spread of the disease.) àrùn; òkùnrùn ó dènà ìtànkálè àrùn náà.

disprace:n; (There is no disgrace in being poor.) ègàn ; ìtijú; èté; ojútì ko sí èté nínu àìlówó

disgrace: v; (He openly disgraced him.)

dójú ti; té o dójú tì í ní gbangba.
disguise: v; (She disguised her voice clererly.)  parade ó yí ohùn rè padà wéréwéré. 

disguise: n; (I didn’t recorgnise him-he was in disguise.) ìbòjú; ìparadà. N kò da mò; o wà ní ìparadà.

disgust: n; (The idea of smoking fills me with disgust.) sísú; ìkó-ní-ìríra òrò sìgá mimu ti sú mi.

disgust: v; (It disgusts me to see him abusing his wife in the public.) su; kó ní ìríra o kó mí ní ìríra kí n máa ríi kí o máa bú ìyàwó r`ní ojú gbogbo aye.

dish: n; (He bought new dishes.) àwo oúnje ó rá àwon àwo oúnje tuntun.

dish: v; (Can you dish out everything for me?) bù oúnje sínú àwo. N jé o lè bù gbògbo rè sínú àwon fún mi?

dishonest: adj; (He wa dishonest to me.) aláìsòótó; ayédèrú ó se aláìsòótó sí mí. disinfect: v; (This nurses disinfected the hospital wards.) fi oògùn lé síwájú. Àwon onísègun fi òògùn lé àrùn síwáju ní ìbùgbé àwon aláìsàn ní ilé ìwòsàn náà.

dislike: v; (I dislike dogs.) kóòríra mo kóòríra àwon aja.

dislike: (I have a strong dislike of modern music.) ìkoòríra mo ní ìkoòríra àwon orin ayé òde òní.

disloyal: adj; (He is disloyal to his country.) alálòótó ó jé aláìlóòtò sí orílè-èdè re.

dismal: adj; burú; ní ìbànújé sókùnkùn Iroyin náà buru bí í ti àtèyìnwá.(The news was as dismal as ever.

dismay: (She expressed dismay at what had occurred.) èrù; ìdààmú;ìfòyà ó fi ìfòyà rè hàn lórí ohun tó selè.

dismay: v; (He were all dismayed at his refused to co-operate with us.)

dààmú; foya. Gbogbo wa la dààmu nítorí àìgbà rè láti se tiwa.

dismiss: v; yo(He planned to dismiss the worked from the company.) kúro; ó gbìyànjú láti yo òsìsé náa kúrò níbi ìsé.

disobey: v; (He disobeyed his parents.) se àìgboràn ó sàìgboran sí àwon òbí rè.

disobedience: n; (He was punished for his disobedience.) àìgboran. Wón bá a wí fún àìgboràn rè.

disobedient: adj; (I was very disobedient to my father.)aláìgboràn mojé aláìgboràn sí bàbá mi.

disorganise: v; (He disorganised our plans.) dà rú ó da àwon erò wa rú.

dispatch: v; rán lo kíákíá. Àwọn Améríka ran àwon okò ogun won lo sí àgbégbe náà.

dispatch: n; ikò tí a rán nísé. Ìjòba kí àwon ikò tí wón rán lo sí ibi ìpètu sí ìjà náà káàbò.

dispense: v; (Government wellcome the clespatch of the peace keeping force.) pín fún okùnrin náà pín àwon ohun èlò ìlera fún àwon aláìní.

dispensary: n; (The man dispensed free health care for the poor.) (He went to dispensary to by medicine.) ilé egbò igi; ilé oògùn ó lo sí ilé egbò igi lati lo ra oògùn.

disperse: v; (The wind dispersed the clouds.) fúnkà; túká. Atégùn tú kùrukùru náà ká.

display: v; (He displayed his goods for sale.) tò ó se àfihàn àwon ojà rè fún tità.

display:n; (They put the documents on permanent display in the British Muscum.) àsehàn; ayeye wón kó àwon ìwé náà sínú gbòngàn àwon Gèésì fun àfihàn t;o pé títí.

disposal:n; (Bomb disposal is not common.) (The books are at my disposal.) ìkáwó; Àwon iwé náà wà ní ìkáwó mi. Ìju-nnkan-nù; ìda-nnkan-nù Tà. Ìtèsíwájú nípa títa awon ohun ìní náà ní à n réti láì pefurther asset disposols are expected soon.

dispose: v; (Various objects were disposed on the desk in front of her.) (We should find a better way of disposing of household waste.) tò orísìírisìí àwọn nnkan ni won to sí orí tábìlì ìkòwé tó wà níwájú re. jù nù; so nù ; dà nù. A ní láti wá ònà tó dára láti máa da awon ìdòtí ilé nù.

dispute: n; (There was disput among them.)

ìjiyàn; àríyànjiyàn. Aríyànjiyàn wà láàrin won.	

dispute: v; (They disputed what they should do.) jiyàn sí, lòdì sí won lòdí sí ohun tó yé kí wón se.

disrespet:n; (I meant no disrespect by the remank.) àìbòwòfún; àìboláfún. N kò gbèrò àibòwòfún pèlú ìsesí mi yen.

disrespectful: adj; (The child was disrespecful to her parents.) jé aláìbòwòfúnni ómo náà se alaibòwò fún àwon obíi rè.

dissatisfaction: n; (Many viewers have written to express their dissatifaction current programmes.) àìtélórùn òpòlopò ònwòye ló ti kòwé láti fi àìtélórùn won hàn pèlú àwon ètò tó n lo.

dissatisfied: adj; I am throughout dissatisfied with your work.) sàìtemi lórùn Isée re sàìtémi lorun pátápátá ni.

dossolve: v; (Water dissolves salt.)yó omi máa n mu iyò yó

distance:n; (What is the distance between the two houses.) ààyè; ìtakété; àlàfo kí ni àlàfp tó wa láàrin awon ilé méjèèjì náà?.

distance: v; (She need to distance hereslf from them.) yapa; jìnà o ye kó jìnà sí won.

distant: adj; (The airport is about ten miles distant from the city.) jìnà; jìn. Pápákò òfuurufú náà fi bíi máìlì méwàá jìnà sí ilú.

distemper: n; (My dog is suffering from distemper.) (I painted my house with distemper.) arùn ajá-òpóòrò. Àìsàn òpóòrò n se ajá mi. òdà ìkunlé mo fí òdà kún ilé mi.

distill: v; (He distilled fresh water from sea water.) pon(otì) ó pon omi òtun lati ara omi òkùn.

distinct: adj: (She hast a distinct advantage over her opponent.) yíyàtò; yanjú; hàn; yà sápá kan ó ní ànfààní to yato lóríi tí àwon alátakò rè.

distinction: n; (He drew a distinction between bith and wealth.) ìyàtò; híhàn gbangba. Ìtayo ó fi ìyàtò hàn láàrin omo bíbí àti orò.

distinguish: v; (The twins are so alike that I can’t distinguish one from the other.) sàmì sí lótò; mò yàtò; se ìyàtò. Àwon ìbejì náà jora won dé ibí pé n ko le mo òkan yàtò sí ekeji.

distress: n; His wild behavious was a great distress to his mother. ìsé; ìpójú; ìrora; ìnira. Ìwà búburú re je ìnira nla fún ìyá rè.

distress: v; (I am much distressed to hear the news of your wife’s death.) mú ìpónju tàbí ìnira bá. Gbígbó tí mo gbó ikú ìyàwó rẹ̀ inú ìrora bá mi.

distribute: v; (The teacher distributed books in the classroom.) pín olùkó pín àwon ìwé náà ní yàrá ìkàwé.

distribution: n; (They could not agree about the distributon of the profits.)ìpínfúnni; pínpín won kò lè fenu kò lórí bí won yoo ti máa se ìpin fúnní èrè tí won bá je.

district: n; (He hails from Western District.) ekùn; egbègbè; sàkánì ó wá láti ekùn Ìwò oòrùn.

disturb: v; (Please don’t disturb yourself.) rú sókè; tó; dí lówó; yo lénu Jòwó má yo ara re lénu.

distrubance: n; (I don’t want any disturbance.) ìyolénu; ìdààmú; ìdílówó. N kò fé ìyolénu kankan.

ditch: n; (He is as dull as ditch water.) yàrá; ògbun ; kòtò ó tiiri bí omí inú kòtò.

divan: n; (My father sat on a divan bed.) àga ìgokòó gígùn onítìmùtìmù tí ó se é sùn. Bába mi jòkó lórí àga onítìmùtìmù tí ó se e sun

dive:v; (He dove into the bridge and rescued the drowning Child.) mòòkùn; bé sínú omi, ó bé sínú omi láti orí afára, o sì gba omo to fè mu omi yó náà là.

dive: n; (He had a graceful dive.) ìmòòkùn nínú omi ó se ìmòòkùn to dáa nínú omi.

diver: n; (The boy is a good diver.) amòòkun. Amòòkùn gidi ni omokùnrin náà.

divide: v; (The divided the money among them selves.) pín; yà nípá. Wón pín owó náà láàrin ara won.

divide: n; (I stood at the divide of the two separate river.) ààlà mo duro ní ààlà àwon odò méjèèjì.

divine: adj; (He needs divine mercy.) ohun tí òrùn; ti olórun ó nílò àànù olórun. divinity: n; (He studied about the divinity of jesus Christ.) ìwà òrun: ìwà olòrun ó kó nípa ìwà òrun Jesu kírísítì.

divorve:v; (She is divorcing her husband.) yà kò sílè ó ti s ko oko rè sílè.

divoice: n; (They have agreed to have a divoice.) ìkòsílè oko tàbí aya wón ti gba láti ní ìkòsílè.

dizzy:adj; (Chimbing so high made me fee Dizzy.) lóòyì Gígun orí òkè gíga lo jé kí òyì n kó mi lójú.

do: v; (What are you doing this evening.) (What did you eat yesterday.) se kí lo n se ni ìròle yìí. kí- àtóka ìbéère kí lo je lánàá kó nípa mo n kó nipa ede Gèésì.

dodk: n; (I am doing English language. (I am studing English) (The ship was in dock.) ibi ìkan-okò okò ojú omi nàá wà nibi ìkanko/atunse. Ó ti dúró nínú àga ìrojó ní òpò ìgbà.(He has been in the clock several times already.)

dock: (The ferry is expected to duck at 6). gúnlè sí èbítè okò ojú omi náà gbódò gunle sí èbútè ní aago méfa.

doctor: n; (The man has doctor of law.) onísegùn onísègùn ni bàbà mi my father is a doctor oyè òmòwé okùnrìn náà ti gba oyè òmòwé nínú ise òfin.

dodge: v; (He dodged the arrow.) ètàn; yí sí apákan lójìíji; yè bèsé.

dodge: n; (Whan it comes to getting off work, he knows all the dodges.) ogbón èwé ; ogbón àyínnìke. Tí o bá dí kí a máa gbàyè kúrò níbi isé ó mo gbogbo ogbón àyínnìke.

doe: n; (The hunter killed a doe.) abo àgbònrin ode náà pa abo àgbòrín kan.

does: v; (He does it everyday.) se o máa n se e lójoojúmó.

dog: n; (I could hear a dog barking.) ajá mo n gbó tí ajá n gbo.

dogfish: n; (The fisherman killed a dogfish.) ajádò. Apeja náà pa ajádò kan.

doll: n; (She is quite a doll.) omo-lángidi. À fi bí omolángidi.

dollar: n; (You will be paid in American dollars) owó fàdákà àwon aláwò funfun owó fàdákà àwon aláwò funfun ó fi san fún o

domestic:adj; (Goat is a domestic animal.) ti ilé; tí a tù lójú. Ewúrè jé eran ilé.

dominate: v; (She always says a lot of they in in the meetings but she doesn’t dominate.) gàba lé lórí, se olúwa lé lórí ó máa n so òpòlopo òrò nínú ìpàdé sùgbón kò je gàba.

domination: n; (Domination of men over every thing should be stopped.) ìjegàba Ìjegaba àwon okùnrin lórí ohun gbogbo gbódò dópin.

dome: n; (The dome of our church building is very good.) orùlé gongo ti ìdí rè se rìbítí òrùlé ilé ìjósin wa tó se ríbítí náà ára gidi.

domino: n; (The boy is playing with a domino.) igi gbogila tí a kun lódà tí a fi àmì tóó tòò lóó sí lára. Omokùnrin náà n ti igi gbogila ti a kùn tí a fí àmì tóo tòò sí lára seré

dominion: n; (Soon the whole country was under his sole dominion.) ìjoba; ilè oba láìpé yìí ni gbogbo orílè-èdè yìí wà lábé ìjoba rè pátapáta

donate: v; (The charirman donated a car.) fi èbùn fún ; dá alága náà fi èbùn okmo ayókélé sile.

donor: n; (The man was among the donors.) olù fi èbùn silè; olùdá okùnrin náà wà lára àwon to fi èbùn sílè.

done: adj; (Whan you are done perhaps I can say something.) (The meat isn’t quite done yet.) parí Tí o bá are parí bóya mo lè so nnkan kan. Pé, tó. Eran náà ko tìí jina tó.

done: v; (I have done it.) se mo ti se e.

donkey: n; (The man is feeding his donkey.) kétékété okùnrin náà n fún kétékété rè lóúnje.

don’t : v; (Please don’t go.) má se. Jòwó má se lo. doodle: v; (I often doodle when I am on the phone.) yára ko nnkan tàbí ya nnkan mígbà tí a n sòrò tàbi se ohun mìíràn. Mo máa n yára ko nnkan sílè nígbà tí mo bá n lo èro ìbánisòrò.

door: n; (Open the door.) ilèkùn; ojú ònà sí ìlèkùn

door-step:n; (The police turned up on their doorstep at 3 o ‘clock this morning.) àbáwole; enu ònà. Àwon olópàá dé enu òná won ní agogo méta àárò yìí.

doorway: n; (The boy stood beside the Doorway.) férèmù enu ònà omo náà dúró légbèé férémù enu ònà.

dormitary: n; (The school has many dormitories.) iyàrá òpò ènìyàn; ibùgbé òpò ènìyàn. Awon ibùgbé tí òpò èrò n gbé po nílé-iwe náà.

dose: n; (Repeat the dose after 12hours if necessary.)ìwon oogùn ti a lè mu léèkan. Tún ìwòn òogùn náà lo tí o bá seé se léyìn wàkati méjìla.

dot: n; (There ara dots above the letters i and j.) àmì àmì wà lórì leta i àti j.

dot: v; (Why do you never dot you i ?) se àmì sí kí lo de ti o kìí fií fi ami sí i re?

double: adj: (She earns double the work she does.) méjì; ìsépo meji; ìlópo méjì ó n gba ìlópo méjì owó ise tó n se.

double: adv: (I had to bend double to get under the table.) léèmaji; ni ilopo meji mo ní láti bèrè ní ìlópo méjì ju ti àtèyìnwá lo láti lè bó sí abé tábìlì náà.

double:n; (He gets paid double for doing the same job I do.) ìoópo meji o n gba ìlópo owó mi fifun sise iye isé tí mo n se. double: v; (She doubled the blanket and put it under her head.) ló po lónà méjì; jé ìlópo lónà méjì sé po léè méjì ó sé aso ìbora náà po léèméjì o sì fi rorí.

double:decker : (I sat on the upper deck of the double decker bus.) okò alágbèékà méjì mo jókòó ní okè okò alágbèékà méjì.

doubt: n; (There is no doubt at all that we did the right thing.) iyèméjì ; ìréfòó; àìdánilójú; àníàní kò sí àní-àní pé a se ohun tó tó.

doubt: v; (There seems no reason to doubt her story.) siyèméjì; se àní-àní ; ìméfòó ko sí ìdí kan tí ènìyàn fi le se àní-aní nipa ìtan rè 

doubtful: adj; (He is doubtful about accepting extra work.) níyèmeji; sìyèméjì ó si n sigèméjì nipa gbígba àfikún isé.

dough: n; (Knead the dough properly.) ìyefun po ìyefun náà dáradára

dove: n; (He killed two doves.) àdàbà ó pa àdàbà méjì.

dove: v; (He dove in the river.) mòòkun ó mòòkun nínú odo.

doze: v; (He dezed off in front of fine.) tòògbé; sùn fééré ó tòògbé níbi tí ó ti n yéná.

dozen: n; (Give me a dozen please.) méjìlá fún mi ní méjìlà jòwó.

drag: v; (He was dragging his feet) (The meeting really dragged.)wó ó n wo èsè nílè. Fà; falè Ipade náà fà.

drag: n; (Having to work late every day is a drag.) ohun tí o fale;ohun tí o sún ènìtàn sisise pé ní gbogbo ojó jé ohun tí o sún ènìyàn

dragon:n; (Dragon is a dangerous animal.) eranko tó jo ònì tí ó si léwu dírágónì Dírágónì jé eranko to léwu.

dragonfly: n; (Dragonflies are often seen over water.) lámilámi. A máa n sábàa rí àwon lámilami lórí omi.

drain: v; (Leave the dishes to drain.) fa omi kúrò; mú gbe fi àwon abó náà sílè kó gbe.

drain: n ; (The drain is blocked.) ihò omi-ilò tí omi n gbà. Ihò omi náà ti dí.

drake: n; (I have a drake.) ako pépéye mo ní ako pépéye kan.

draught: (Can you close the door? There’s an awoful draught in here.) (They were playing with draught.)aféfe tútù. N jé o lè palèkùn dé? Aféfé tútù tó bami lérù wà nínú ilé níbì. ohun ìsire tí a n ta lórí páálí won n fi ayò ti a n ta lórí páálí seré.

draw: v; (The meeting was drawing to a close.) (He drew the chir close to himself.) (She drew back the curtain across the doorway.) ya àwòrán mo lè ya àwòrán tó dára sún mó Ìpàde nána tí n sún mó ìpari. wó/fà ó wó aga náà móra. sí tàbí tì ó da aso títa náà bi enu ònà padà.

drawbridge:n; (They lowered the drawbridge.) afáraá àsún-síhìn-ín-sín-sóhùn-ún wón ré afárá àsún-sìhùn-ín-sún-sòhùn-ún náà sìlè.

drawer: n; (He kept the money in his drawer.) irúfé àpótí kan tí a so mó tábìlì, tí a n pa nnkan mó sí ó fi owó náà pamo sínú apótí lábìlì rè.

drawing-board: n; (He broke the drawing-board.) pátáko ìya-nnkan ó ya pátáko ìya-nnkan náà.

drawing: pín: n; (He bought a packet of drawing pin.) irúfé abéré tí o ní idí pelebe tí a fi n mu ìwe mó pátákó ó ra péélí abéré ìmúwèé mó pátáko.

dread: n; (The prospect of growing old fills me with dread.) èrù; ìfòyà. Èrù ogbó n bà mú

dread: v; (We all dread to think whet will happen if the factory is closed.) nífóyà; bèrù. Gbogbo wá nífoya láti ro lo le selè tí ijé-isé náa bá di détì pa. dreadful: adj; (The noise is dreadful.) bami lérù; fom láyà. Ariwo náà bami lérù.

dream: n; (I had a dream yesterday.) àlá mo lá àlá kan lánàá.

dream: v; (She claims she never dream.) lá àlá o máa n so pé òun kìí lá  àlá. 

drench: v; (We were caught in the storm and got drenched.) re; rin’fi omi rin. Ojò pa wa a sì rè.

dress: n; (He gest no dress sense.) aso wíwò; òsó kò mo aso ó wò/ kò maraá mù. 

dress: v; (He dressed himself.) woso. Ó woso fún ara rè.

dressing table: n; (She sat at the dressing-table combing her hair.) tábìlì onídíngí ó jókòó síwáju tábìlì onídíngí ó n yarun.

dressmaker:n; (I took my mother’s cloth to the dressmaker.) olùrán aso obìnrin; aránse obìnrin tà mo mú aso ìyá mi lo sí òdò aránso tà.

drill: n; (He bought a hand drill.) ohun èlò tí a fi n lu ihò ó ra ohun èlò ìluhò olówó.

drill: v; (He drilled hole in the frame.) (The students were drilled to leave the classroom quickly when the fure bell rang.) lu ihò o lu ihò sí ara férémù náà. Kó Won kó àwon akékòó náà bí wón se lè fu yàrá ìkàwé sìlè kíakía nígbà tí agogo pé iná sé yo bá dún.

drink: n; (Can I have a drink?) ohun mimu.N jé mo lè rí ohun mímú?

drink: v; mu (He drink water.) o mu omi.

drip:n; ohun tí o n ka’n. A gbé kete sí ojú ibi tí àjà tí n jò kí o lè ma gba omi tí o n kan sílè.

drip: v; (We put a bucket under the hole in the roof to catch the drips.) kán sílè omí nnkan sára ìgànná.

drive: v; (Water was dripping down the walls.) (Don’t drive so fast.) (Could you drive me home.) Hinger drove her to steal.) darí ; wà máse wa okò sáré. Fi oko gbé. N jé o lè gbe mi dele Sún Ebi ló sún débì kí o jalè.

driver: n; (She climed into the drive’s seat.) awakò ó gun orí ìjikòó awakò náà

drizzle: n; (A light drizzle was falling.) òjò weliweli òjò weliweli n rò.

drizzle: v; (Drizzle the lemon juice of the fish.) fi omi/nnkan domí wón fí omi osàn wewe náà won eja yen.

droop: v; (Our spirits droop when we heard the news.) ro; sorí ko; rè sílè okàn wa rè sílè nigbà tí a gbò ìròyìn náà

drop: v; (Be careful not to drop the plate.) (He staggared in and dropped into a chair.) (She expects everyone to work till they drop.) já bó ; bó sóra mase jé kí abó náà bó Subu sínú nnkan. Ó n fese kólè wolé ó sì subú sínú àga rè ó fé kí gbogbo ènìyàn máa sisé títí tí yóò fi rè won. dún kù. Níggbèyìn atégùn náà dún ku. At last the wind dropped.

drop: n; (He mixed drops of milk with the cake) (The is a drop in prices.) kíkán ó po kíkan-an wàrá díè mo àkàrà náà. idínku : idínku ti wa lórí iye ojà.

drown: (Two Children drowned after falling into the river.) mumi yó; kú sínú omi omo méjì mumi yo léyìn tí won kó somi.

drowsy: adj; (The tables may make you feel drowsy.) tòògbé; lóra; fà oògùn onkoro náà le jé kí o máa tòogbé.

drowsiness: n; (The drug may cause drowsiness.) òògbé; fífà. Oògùn náà lè fa òògbé.

drum: n; ìlù (He played his drum.) ó lu ìlù rè.

drum: v; (Who is drumming?) lu ìlù Ta ní o n lu ìlù?

drummer: n; . (The drummer are dready to play their drum.) onílù. Gbogbo àwon onólù náà ti se án láti fi ìlù won sere

drumstick: n; (I lost my drumstick white dancing.) òpá ìlù; gòngó mo so òpá ìlu mi nú bí mo tì n jó.

dry: adj; (He store the onions in a dry place.) gberefun ó kó àwon alùbósà náà pámo sìbí tó gbe.

dry: v; (The paint hasn’t dried yet.) gbe odà náà kò tíì gbe síbè.

duck: n; (He feeds his ducks everyday.) pépéye ó máa n fun àwon pépéye rè lóúnje lójoojumó.

duck: v; (He had to duck as he came.) te orí; bèrè orùn o bèrè orùn nígbà tí ó fé gba enu ònà wolé.

due: n; (She is a slow worker but lo give her due she does try hard.) gbèsè; ètó òsìse tó màa n fà ni sùgbón rí a bà le fún un létòo re o mura sísé.

due: adv; (The village lies 5 miles due our town through the door.) lápá.Abúlé náà jé ibùso márùn-ún lépá ilúu wa.

due: adj; (Rose is due to start school.) to asiko ; tó ti tó. Rose ti tó bere ilé ìwé.

duke: n; (The man is a duke.) okùnrin olókìkì olólá tí o ní ipò gíga olókìkì àti onípò gíga ní okunrin náà.

dull; adj; (The programme is a dull programme.) (He eyes were dull.) (The Child is too dull.) (The gate shut behing him with a dull thurd.) (The sky is dull.) (He had a dull pain.) (Maket is dull today.) tí ó sún ènìyàn. Ètò náà jè eto to súnní tó ko dá sasa ojú rè kò dada sasa. Go: Omo náà ti gò ju. Tí dún sókè Ikèkùn náà tí lèyìn rè láìsí ariwo. tí ko mó gaara ojú òrun kò mó gaara. Tí ko fi béè tabí tani púpò. Ara tí ó n ró kò pò. Tí kò yá Ojà ko yá lónìí.

dull: v; (The tablets they gave him dulled the pain for a while.) (He felt dulled and stupid with sleep.) dín kù. Awon oògùn oníkóro tí wón fún un dín irora rè kù fún ìgbà díe. mú gà; mú dè. Orun mú un dè.

dumb: adj; (She was born dumb.) yíyadi: yadi A bíí pèlú yíyadi.

dumb: v; (The BBC denies that its broadcasting has been dumbed down.) dín nnkan kù BBC ta ko pé ìgbóhìn sí afefe àwọn ti dúnkù.

durmmy: n; (My mother has a talor’s dummy.) (Don’t just stand there’you dummy.) àwòrán èrè. Iyá mi ní àwòrán ere aránso. Òmùgò; aláìnílàákaye. Mà kàn dúró síbè sá; ìwò òmùgò yìí.

dump: v; pa tì ; kó dà sí ibi kan. Awon kan kàn máa n da ìdòti won wínú odo.

dump: n; (We have to take our own rubbish to the council rubbish dump.) ibi ìdalèsí; ibi ìdòtí. A ní láti ko àwon ìdoti wa lo sí ibi ìdale sí ìjoba.

dumpling: n; (I love to eat dumpling after food.) ìyefun tí a se sóbè mo fèràn láti màa je ìyèfun tí a se sóbè léyìn oúnje

dungeon: n; (Throw him into the dumgeon.) ògbun nla tó sókùnkùn. Gbé e jù sínú `dogbun nlá náà.

during: prep: (I will se you during dry season.) ni ìgbà; ni àkókò. N ó rí o ní àkókò èèrùn.

dusk: n; (The street lights came on at dusk and go off at down.) kò-rí-ni-kò-mo-ni; àsìkò tí ilè n sú In;a àwon òpópónà tán nígbà tí ilè n su ó sì kù nígbà tí ilè n mó.

dusky: adj; (There was dusky light inside the cave.) léúléú. Ìmólè léúléú wà nínú `hò náà.

dust: n; (The furmiture was covered in a thick layer of dust.)ìdòti eruku. Ìdòtí eruku ti ó ki àwon aya náà.

dustbin: n; (I saw a mouse in the dustbin.) ìkólè mo rí eku ilé nínú ìkóle náà

duster: n; (He cleaned the blackboard with a duster.) ìpankanré ó fi ìpankanré pa ojú pátákó náà ré.

dustman: n; (The dustman carried some rubbish on his head.) okùnrin kólèkódòtí okùnrin kolékódòti náà ru ìdòtí sóri.

dustpar: n; (Dustpar is good for domestic use.) ìkólè Ikólè dára fún èlò ilé

duty: n; (It is the duty of a doctor to try to keep people alive.) (The man didn’t pay his exise duties.) ojúse ojúse onísègùn ni láti gbiyanju láti mú ke èèyàn wà láàye. Owó ibodè. Okùnrin náà ko san owo ibodè.

dwarf: n; (He is a short as a dwarf.) aràrá ó kúrú bí aràrá.

dwarf: v; (Our little dingly was dwarfed by the big yacht.) mú tabí eni pé ó kéré òkò ojú nlá náà mú òkò ojú omi kékere wa kere ni wíwo lójú

dye: v; (I am sure she dyes her hair.) re láró ó dá mi lójú pé o máa re irun rè láró.

dye: n; (I like blue dye.) aró mo féràn aró olómi búlúù.

dynamite: n; (He broke the stone with dynamite.)ètu alágbara tí a fi n fó òkúta ó fi èti alágbára tí a fi n la òkúta fó òkúta náà