Àwòrán ará òwò Nàìjíríà
Ìrísí
(Àtúnjúwe láti Aworan ara owo Naijiria)
Àwọn Owó Nàìjíríà àti àwòrán tí ó wà lára wọn.
N1 - Náírà kan (Herbert Macaulay)
N5 - Náírà márùn-ún (Alhaji Tawafa Balewa (1912-1966))
N10 - Náírà mẹ́wàá (Alvan Ikoku (1900-1971)
N20 - Ogún náírà (Murtala Mohammed (1938-1978)
N100 - Ogọ́rùn-ún naira (Chief Ọbáfẹ́mi Awólọ́wọ̀ (1909-1987))
N200 - Igba naira (Alhaji Ahamadu Bello (1909-1966))
N500 - Ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀ta naira (Dr Nnamdi Azikiwe (1904-1996))
N1000 - Ẹgbẹ̀rún naira (Alhaji Aliyu ma0-Borno àti Dr Clement Isong)