Bolatito Aderemi-Ibitola
Ìrísí
(Àtúnjúwe láti Bolatito aderemi ibitola)
Bolatito Aderemi-Ibitola (bii ni Ọjọ kokanlelogun, Oṣu kini, Ọdun 1993)[1] je omo bibi ilu Eko, Naijiria. O si lo si ilu Amerika ni odun 2000 o si pada si Naijiria ni odun 2014. Bolatito gba iyi eko Masters ninu eko ikopa ijinle ni Tisch School of the Performing Arts, yunifasiti New York. O gba iyi eko Bachelors ninu eko ibaraenisoro ti o dojuko sise agbejade eto ori amohunmaworan ati fiimu pelu imo oselu ni koleeji Allegheny.[2] Bolatito, ti o je ayaworan ti o n sise lori ikopa ati ibaraenisepo, farahan gegebi olubori 'ART X Prize with Access' ti odun 2018 o si gba ebun owo milionu kan naira ni ojo ketadinlogbon, osu kefa, odun 2018. O ma se agbejade eleniyan kan ni ART X Lagos ninu osu kokanla, odun 2018.[2]
Awon Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "ABOUT". TAI. 1993-01-21. Retrieved 2018-10-13.
- ↑ 2.0 2.1 Onyeakagbu, Adaobi (2018-06-29). "Bolatito Aderemi-Ibitola wins N1,000,000 ART X Prize". Pulse.ng. Archived from the original on 2018-07-06. Retrieved 2018-10-13.