Hóséà Ayoola Agboola

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Hosea Ayoola Agboola)
Jump to navigation Jump to search

Sínétọ̀ Hosea Ayọ̀ọlá Agboọlá tí orúkọ ìnagijẹ rẹ̀ ń jẹ́ Alleluyah (tí a bí ní Ọjọ́ kẹtàlá oṣù kẹjọ ọdún 1960) jẹ́ ọmọ bíbí ìlú Ìbàdànìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Òun ni igbákejì alámójútó-ẹgbẹ́ nílé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà ọ̀wọ́ keje. Ó jẹ́ olùṣòwò àti àgbà ọmọ ẹgbẹ́ òṣèlú People’s Democratic Party ní ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́.[1] Lọ́dún 2003 sì 2015, ó jẹ́ kọmiṣọ́nnà ní ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́. Ẹlẹ́sìn ìgbàgbọ́ ló ń ṣe. Láìpẹ́ yìí, Gómìnà ṣèyí Mákíndè yàn án gẹ́gẹ́ bí alága ìgbìmọ̀ agbaninímọ̀ràn fún ìjọba tuntun lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú People’s Democratic Party. [2][2]

Àwọn Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Fresh crisis hits Oyo PDP as ex-Deputy Senate Whip resigns membership". The Eagle Online (in Èdè Bosnia). 2018-05-02. Retrieved 2019-11-18. 
  2. 2.0 2.1 "Makinde Appoints Senator Hosea Agboola As Advisory Council Chairman". Western Post News. 2019-06-11. Retrieved 2019-11-18.  Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; name "Western Post News 2019" defined multiple times with different content