Ilé Ìdáná
Ìrísí
(Àtúnjúwe láti Ile iidana)
Ilé Ìdáná jẹ ìyára kan nínú ilé tí a tí ń ṣe oúnjẹ tàbí ipalemo oúnjẹ ni ilẹ kàn tabi ilẹ oúnjẹ títà. Nínú Ilé ìdáná ayé àtijó, a má ṣe àwárí awọn nǹkan bí, àbò, igi ìdáná, ijoko, àmù, ikòkò, àti bẹebeelo.