Ilu Ọyẹ́

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Ilu Oye)

Yemitan

Yoruba oral literature

Poetry

Ijala

Literature

Ọladipọ Yemitan

Ijala Aré Ọdẹ

Itan ilu Oye ati Igbeti

Oye

Igbeti

Itan Ilu Ọyẹ́ ati Ìgbẹ́tì Ojú-Ìwé 39-41.[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Alaye: Ọyẹ́ ati Ígbẹ́tì jẹ meji ninu awọn ilu ilẹ Yoruba. Itan bi nwọn ti ṣe dá ilu mejèji yi silẹ ni a sọ ninu ijalá yi. Ilu Ọyẹ́ tit u tipẹ ṣugbọn Ìgbẹ́tì ṣI wà sibẹ-sibẹ. Lẹhin itan ilu mejèji yi. Ijalá yi tun ki oríkì awọn ara ilu mejèji.

Aponle Ogun

Ogun

Apọnlé Ògún Ojú-Ìwé 42-43.[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Alaye: Ó jẹ àṣà awọn ọdẹ lati ma ṣe apọnlè Ògún ti noẉn gbagbọ pe on ni o nse akoso iṣẹ ọdẹ, on ni o si ndabobo gbogbo awọn t’o nṣe ọdẹ.


Omo Odu Apanada

Odu

Ọmọ Òdù Apànàdà Ojú-Ìwé 43-44.[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Alaye: Eyi yi jẹ oriki awọn Ijẹsa. Gẹgẹbi mo ti sọ ni ibẹrẹ iwe yi, o jẹ àṣà awọn ọdẹ lati ma ki ara wọn bi noẉn ba pejọ. Bi ọkan ninu wọn ba jẹ ọmọ Ijẹsa. Ijala yi ni nwọn yio fi ki i ni awujọ ọdẹ.

Idi re ti Onikoyi kii fii je okete

Okete

Onikoyi

Idi rẹ̀ ti Onikoyi kì i fi í jẹ oketé 34.[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Alaye: Ni Ilẹ Yoruba, idile kọkan l’o ni ewọ̀ tirẹ̀. Idile miran wà ti kò gbọdọ fi ẹnu kan pẹpẹiyẹ; idile miran wà ti ọmọ ibẹ ko gbọdọ jẹ ejò: idile miran si wà ti ọmọ ibẹ ko gbọdọ fi agbo wẹ ọmọ. Ibomiran wà ti ọmọ ibẹ ko gbọdọ fi omi gbigbona mọ́ ara bi obinrin ba bimọ, ati bẹbẹ lọ.

Awọn ọmọ Ọlọfa Ojú-Ìwé 35-36.[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Alaye: Ijalá jẹ apẹrẹ ohun ti o ma nṣẹlẹ nigbamiran nigbati baba kan ba ku, ti o fi awọn ọmọ ati ohun-ini silẹ. Ohun ti i ma ṣẹlẹ nip e olukuluku ninu awọn ọmọ rẹ̀ yio bẹrẹsi dù lati ní ipin ti o tọ́ si on ninu ogun baba wọn, olukuluku ko si jẹ gbà ki nwọn fi ọbẹ ẹhin jẹ on ni iṣu.

Olobùró ati Ẹkùn Ojú-Ìwé 37-38.[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Alaye: Gbobgo enia ni o ma bẹru ẹkùn nitori agbara ati ekanna rẹ̀; ṣugbọn ọkunrin kan gboju-gboiya pe on kò ni i sa bi on ba pade ẹkùn. O ti gbojule ọfa ati ogun rẹ̀.

Iwe ti a yewo[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ọladipọ Yemitan (1988) Ijala Aré Ọdẹ University Press Limited, Ibadan, ISBN 0-19-575217-1.