Orin Ìmọ́tótó
Ìrísí
(Àtúnjúwe láti ORIN ÌMỌ́TÓTÓ)
ORIN ÌMỌ́TÓTÓ
Wẹ̀ kí o mọ́
Gé èékánná rẹ
Jẹun tó dára lásìkò
Má jẹun jù.
Ìmọ́tótó ló le ṣẹ́gun ààrùn gbogbo
Ìmọ́tótó ló le ṣẹ́gun ààrùn gbogbo
Ìmọ́tótó ilé, Ìmọ́tótó ara
Ìmọ́tótó oúnjẹ
Ìmọ́tótó ló le ṣẹ́gun ààrùn gbogbo