Jump to content

Reggie Tsiboe

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Reggie tisboe)

Reggie Tsiboe ( tí abí ní ọjọ́ keje oṣù kẹsàán ọdún 1950) jẹ́ oníjó, olù dà àwọn ènìyàn lárayà àti olórin ti a bí ní orílẹ̀-èdè Ghana àti Britian, ó sì tún jẹ ọmọ ẹgbẹ́ disco Boney M. láàrin ọdún 1982 sí 1986 àti laáàrin ọdún 1989 sí 1990.[1]

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. Google