Sadiiki

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Sadiiki (Chadic))
Jump to navigation Jump to search

Chadic

Gẹ́gẹ́ bí ọ̀rọ̀ New man (1992:253) ó ṣọ́ pe o to nǹkan bi ogóje èdè Chadic gẹ́gẹ́ bí maapu ṣeṣe àfihàn ó tanka èka mẹ́fa nínú ajúwe lati adagun odo Chad nibi tí orúkọ ìdílé ti sẹ̀ wa ti a ṣi ń sọ ni apá kan nìjìríà, Chad Cameroon orílẹ̀ èdè Arìngbùngbùn ilẹ́ Áfíríkà olómìnira àti Niger. Èyí tí ó dára ju tí ó si tan káàkiri ti á ń ṣọ ní èdè Chadic tí a mo si Hausa, tí ó jẹ pe ti á ba fi mìlọnu àwọn tí wọn ń ṣọ èdè kejì ti a ba wo ìgbéléwọ̀n náà a ó ri gẹ́gẹ́ bí èyí to tóbi jù nínú àwọn adúláwọ̀ to n ṣọ èdè náà tì ó sì je pé à yọ Arabiki kúrò ninú rè. Àwọn yòókù tí wọn ń sọ èdè Chadic kò jú ẹgbẹ̀rún kan nìgbà tó o jẹ́ pé àwọn yòókù ko ju perete lọ Newman(1977) wọn pin àwọn Chadic si mẹrin

(1) Èdè Chadic ní wọn ń sọ ni ìwọ̀ Oorun Níjiria ti o sì pín ṣi ẹka méjì ìkan wa ní ìṣọ̀rí agbo mẹrin àwọn wọ̀nyí ní Hausa (22,000), Bole (100), Angas (100) ati Ron(115) Nígbà ti ọ̀kan wà ní ìṣọ̀rí mẹ́ta tí á ṣi se àfihàn rẹ̀ láti ọ̀dọ̀ Bade (250) àti Nalzlm (80), lati Ọwọ Warji (70) ati Boghom(50)

(2) Bio-Manchaca ni èdè tí wọ́n ń ṣọ ni agbègbè Àríwá Cameroon àti Àríwá ìlà Òòrùn Nígiria pẹlu Chad àwọn ẹka mẹta nígbà tí ìkan jẹ mẹjọ, ti a si ṣe àfihàn rẹ lati Ọwọ Tera (50) Bura (250), Kanwe (300), Lamang (40), Mafa 9138), Sukur (15), Daba (36) àti BaChama-Bata 300. Àwọn méjì nínú ẹ̀ka méjì a le ṣe àfihàn wọn láti Ọwọ Buduma (59) ati Musgu (75) Ìpele Kẹta kun fún èdè ẹyọ kan Gudar (66)

(3) Èdè Chadic ní wọn ń ṣọ ní Chad Gusu àti diẹ lára Cameroon àti àringbìngbìn ilé Áfíríkà olómìnira. Èdè náà ní ẹ̀ka méjì tí ó kún fún ẹgbẹ́ ìṣọ̀rí mẹta mẹta tí ó ni ẹka a ṣe àfihàn iṣupọ lórísìíríṣí Ọwọ Kera *51) púpọ̀ nínú àwọn ẹ̀ka wọ̀nyí a le ṣe àfihàn rẹ lati Ọwọ Dangaleat (27) ati Mokulu (12), àti lowo Sokoro (5)

(4) Masa jẹ èyí tí ó gba Ominra tí ó ṣi kún fún orísi, mẹ́san láti ìwọ̀ Òòrùn Gúsù Chad àti Àrìíwá Cameroon. Ní àfikún Masana (212) Musey 120 èyí tí ó sún mọ́ ní Zumaya