Suny Aládé
Ìrísí
King Sunny Ade Olóyè Sunday Adéníyì Adégeyè (MFR), tí a mò pèlú isé won gégé bíi King Sunny Ade je eni tí a bí ní Ojó kejìlélógún, osù September, odún (1946) jé olórin àti akorin pèlú onímò orísirísi ohun èlò orin ìlú Nàìjíríà nínú àsà Orin ti apá ìwò oòrùn ilè adúláwò tí a mò sí jùjú. Ó jé Òkan lára àwon olórin àkókó ti ilè adúláwò láti ní àseyorí kákìjádò ayé, a ti pè e ní òkan lára àwon olórin tó níyì jùlo ní Gbogbo àsìkò. Ó jé olórin Jùjú, African Pop òun ló nilé işé agbórinjáde (I.R.S) Ní osù Erénà (March) odún 2017, wón yàn-án gégé bíi asojú fún egbé ìpolongo ìbò "Àyípadà bèrè pèlú mi" láti owó Mínísítà fún ìròyìn ìlú Nàìjíríà tí orúko rè ń jé LAI MOHAMMED[1]
Ìtọ̀ka sí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "King Sunny Ade - Biography, Albums, Streaming Links". AllMusic. Retrieved 2019-03-14.