Oníṣe:Waliyullah Tunde
Ìrísí
Waliyullah Túndé Abímbọ́lá jẹ́ mùsùlùmí ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, ó sì jẹ́ ọmọ Yorùbá. Ó fẹ́ràn gbogbo nǹkan to bá jọ mọ́ títọ́jú ìmọ̀, pàápàá lítírésọ̀ àti èdè, ó sì fẹ́ràn láti máa mu àwàdà jáde nínú u gbogbo nǹkan,èyí tí gẹ̀ẹ́sì rẹ̀ ń jẹ́ Humorist.
Mo kàn kọ ọ̀rọ̀ kékeré yìí kí Wikipedia le yé fi àwọ̀ pupa kọ orúkọ-ọ̀ mi ni.
Ẹ le kàn sí mi ní waliyullah212@gmail.com fún gbogbo nǹkan tó bá jọ mọ́ ohun tí mo kọ sókè.
Ire àti Àlàáfíà o.