Wikipedia:AOIF
Ìrísí
(Àtúnjúwe láti Wikipedia:Àwọn oníṣe ìmúdájú fùnrawọn)
Àwọn oníṣe ìmúdájú fùnrawọn jẹ́ àwọn oníṣẹ́ tí ó ti tó ọjọ́ mẹrin tí wọ́n ti forúkọ sílẹ̀ tí wọ́n s̀ì ti ṣe àtúnṣe bíi mẹ́wá sí àwọn àyọ́kà. A lè gbẹ̀rí àwọn oníṣẹ́ yí jẹ́ díẹ̀ wípé wọn kò lè dojú àwọn àyọkà rú.