Àtòjọ Àwọn Ìwé-ìròyìn Lórílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Èyí ni Àtòjọ Àwọn Ìwé-ìròyìn tí wọ́n ń tẹ̀ jáde tí wọ́n sìn ń tà lórílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà

Títí di 2014, iye ìwé ìròyìn ojoojúmọ́ tí wọ́n wà lórílẹ̀ èdè Amẹ́ríkà jẹ́ 1,331.[1]

Mẹ́wàá tó gbajúmọ̀ káàkiri jùlọ nínú àwọn ìwé-ìròyìn Amẹ́ríkà[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àwọn wọ̀nyí ni mẹ́wàá nínú àwọn ìwé-ìròyìn Amẹ́ríkà tó gbajúmọ̀ jùlọ ní títàn káàkiri lóòjọ́ lọ́sẹ̀, tí kìí ṣe ọ̀fẹ́. [2]

Rank Orúkọ Ìwé-ìròyìn Àgbègbè tí wọ́n wà Olú ìlú tàbí ìpínlẹ̀ tí wọ́n wà Àpapọ̀ iye tí wọ́n ń gbé jáde Olùdásílẹ̀ Orúkọ Ìṣẹ̀dá lẹ̀ rẹ̀
1 USA Today McLean, Virginia Virginia 1,621,091 Gannett Company
2 The Wall Street Journal New York City New York 1,011,200 News Corp
3 The New York Times New York City New York 483,701 The New York Times Company
4 New York Post New York New York 426,129 News Corp
5 Los Angeles Times Los Angeles California 417,936 Nant Capital
6 The Washington Post Washington D.C. District of Columbia 254,379 Nash Holdings
7 Star Tribune Minneapolis Minnesota 251,822 Star Tribune Media Company
8 Newsday Melville New York 251,473 Newsday Media Group
9 Chicago Tribune Chicago Illinois 238,103 Tribune Publishing Company
10 Boston Globe Boston Massachusetts 230,756 Boston Globe Media Partners

Àwọn ìwé ìròyìn Amẹ́ríkà tí wọ́n ti wà fún ìgbà pípẹ́[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àwọn tó wà ní ìpínlẹ̀ àti àgbègbè kọ̀ọ̀kan[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àtòjọ Àwọn àtòjọ Ìwé-ìròyìn:

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Newspaper Circulation Volume". Newspaper Association of America. 4 September 2012. Archived from the original on 20 January 2016. Retrieved 20 January 2016. 
  2. "Top 10 U.S. Daily Newspapers". Cision. January 4, 2019. Retrieved 2019-10-26. 
  3. About Us", Press-Republican. Originally published as the Plattsburgh Republican, then became the Press-Republican after a merger on October 5, 1942.
  4. "Prospectus for the Columbus Enquirer, January 1828 | TSLAC". www.tsl.texas.gov (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2018-01-18.