Àtojo àwon ìjoba ìbílè ní ìpínlè Èkó nípa bí ènìyàn se pò sí

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Ìpínlẹ̀ Èkó ni agbègbè ìṣakoso marun, èyíinì ni, Ikorodu, Ikeja, Epe, Badagry, àti Lagos Island, tí Ikeja sì jẹ́ olú ìlú ìpínlè Èkó. Awọn agbègbè isakoso àti idagbasoke marun yi ni apapọ ní awọn agbegbe ijọba ibilẹ ogun (20) ati Awọn agbegbe isakoso (metadinlogoji)37 (LCDAs).

Àwon agbègbè isakoso ati idagbasoke yi ni Agbado/Oke-Odo, Agboyi-Ketu, Ayobo-Ipaja, Bariga, Egbe-Idimu, Ejigbo, Igando-Ikotun, Ikosi-Isheri, Isolo, Mosan-Okunola, Odi Olowo-Ojuwoye, Ojodu, Ojokoro, Onigbongbo and Orile Agege.

Ipo LGA Olugbe
1 Alimosho 11.456.783
2 Ajeromi-Ifelodun 2,000,346
3 Kosofe 665,421
4 Mushin 633.543
5 Oshodi-Isolo 1.621.789
6 Ojo 598,336
7 Ikorodu 535,811
8 Surulere 504,409
9 Agege 461.123
10 Ifako-Ijaiye 428,812
11 Somolu 402,992
12 Amuwo-Odofin 318.576
13 Lagos oluile 317,980
14 Ikeja 313.333
15 Eti-Osa 287,958
16 Badagry 241.437
17 Apapa 217.661
18 Lagos Island 209.665
19 Epe 181.715
20 Ibeju-Lekki 117.542

Awọn itọkasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]