Àwọn àyájọ́ ọjọ́ ìsinmi ile Naijiria
Ìrísí
Ile Naijiria ni Àwọn àyájọ́ ọjọ́ ìsinmi to po
Àwọn àyájọ́ ọjọ́ ìsinmi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Isinmi |
Deeti | Awon Akiyesi |
---|---|---|
New Year's Day | 1 January | Àyájọ́ ọjọ́ ìsinmi Ìbẹ̀rẹ̀ Ọdún tuntun. |
Women's Day | 8 March | Àyájọ́ ọjọ́ ìsinmi láti fi bí àwọn Obìnrin ṣe ń kópa láwùjọ wọn jákè jádò àgbáyé. |
Workers' Day | 1 May | Àyájọ́ ọjọ́ ìsinmi fún awon Osise jákè jádò àgbáyé. |
Children's Day | 27 May | Àyájọ́ ọjọ ìsinmi fún àwọn ògo wẹẹrẹ. |
Democracy Day | 29 May | Àyájọ́ ọjọ́ ìsinmi fún isejoba awa arawa ni orile ed Niajiria. |
Independence Day | 1 October | Commemorates the Independence of Nigeria from Britain. |
Christmas Day | 25 December | Christian holiday commemorating the birth of Jesus. |
Boxing Day | 26 December | Christian holiday commemorating the day after Christmas. |
Àwọn àyájọ ọjọ́ ìsinmi tó ma ń yí padà
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Lafikun, orile ede Naijiri ni awon ayajo ojo isinmi kan ti deeti won ma n yi lodoodun:
Ìsinmi | Àwọn Àkíèsí |
---|---|
Mawlid | Ayajo ojo isinmi awon Musulumi, ni iranti ojo ibi Anobi Muhammad. |
Eid al-Adha | Ayajo ojo isinmi awon Musulumi, ni iranti igbafa ojise Olorun Ibrahim lati finu findo fomo re rubo fOlorun Oba. |
Eid al-Fitr | Ayajo ojo isinmi awon Musulumi, fun sisajoyo ipari Osu Awe Ramadan. |
Good Friday | Ayajo ojo isinmi awon omo leyin Kirisiti fun iranti kikan Jesus mo agbelebu. |
Easter Monday | Ayajo ojo isinmi awon leyin Kirisiti fun iranti ojo Ajinde Jesu |