Ántígúà àti Bàrbúdà

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Ántígúà àti Bàrbúdà
Antigua and Barbuda

Coat of arms ilẹ̀ Ántígúà àti Bàrbúdà
Coat of arms
Motto: Each Endeavouring, All Achieving

Location of Ántígúà àti Bàrbúdà
Olùìlú
àti ìlú tótóbijùlọ
Saint John's
Àwọn èdè ìṣẹ́ọbaGeesi
Local languageAntiguan Creole
Orúkọ aráàlúAntiguan, Barbudan
ÌjọbaParliamentary democracy
under a federal constitutional monarchy
Elizabeth II
Rodney Williams
Gaston Browne
Igbominira latowo Ileoba Aparapo
• Ojoodun
1 Osu Kokanala, 1981
Ìtóbi
• Total
440 km2 (170 sq mi) (195th)
• Omi (%)
negligible
Alábùgbé
• 2009 estimate
85,632 (191st)
• Ìdìmọ́ra
194/km2 (502.5/sq mi) (57)
GDP (PPP)2009 estimate
• Total
$1.522 billion[1]
• Per capita
$17,892[1]
GDP (nominal)2009 estimate
• Total
$1.178 billion[1]
• Per capita
$13,851[1]
HDI (2007) 0.868
Error: Invalid HDI value · 47th
OwónínáEast Caribbean dollar (XCD)
Ibi àkókòUTC-4 (AST)
Ojúọ̀nà ọkọ́left
Àmì tẹlifóònù+1-268
Internet TLD.ag
  1. God Save The Queen is the official national anthem but it is generally used only on regal and vice-regal occasions.

Ántígúà àti Bàrbúdà (pípè /ænˌtiːgwə æti bɑːɹˈbjuːdə/ ( listen); Spani fun "atijo" ati "onirungbon") je is a twin-orile-ede erekusu-meji larin Omi-okun Karibeani ati Okun Atlantiki. O ni erekusu meji ninla ti awon eniyan ungbe be, Ántígúà ati Bàrbúdà, pelu awon erekusu kekeke melo kan (bi awon Erekusu Great Bird, Green, Guinea, Long, Maiden ati York).



Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. 1.0 1.1 1.2 1.3 "Antigua and Barbuda". International Monetary Fund. Retrieved 2010-04-21.