Ìṣilọ ati Àyipada lori Àyika Ágbàyè

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Ìṣilọ ati Àyipada lori Àyika Ágbàyè jẹ Ìwadi nipa ipa ti ayipada óju ọjọ kó ninu ìṣilọ ọmọ èniyan ati iṣikuró ni wọn tẹ si ta ni ọdun 2011. Iwadi yii wa lati ẹka èró ni àbẹ àkósó ijọba UK to da lori imọ ijinlẹ̀[1].

Eyi ni wọn pe ni èró Iroyin larin awọn ti oun ṣiṣẹ ni abẹ ójù ọjọ ati ìṣilọ. Iroyin ni Ọjọgbọn Richard Black ti ilè iwè giga Sussex ṣaju rẹ. Ìwadi fi ọwọ si àyọka lori ìṣilọ ati ayipàdà òjù ọjọ. Iwadi yii fi igbèroyin jade lori gbigbè jadè rẹ[2][3][4].

Iwadi yi da lori èró ti wón dè mọlẹ. Iroyin sọpè latara ayipada ójù ọjọ awọn èniyan ni lati duró sibi ti wọn wa. Iwadi fi idi ẹ mọlẹ pe eyi jẹ̀ ki awọn èniyan di tàlàkà latari ìbajẹ ilẹ̀. Iroyin yii jẹ ko gbajumọ pè iṣilọ ni aṣamubadọgba fun ayipada ójù ọjọ[5]. Awọn ólukọwè litirèsọ sọpe ìṣilọ jẹ ọna kan gbogi ti awọn èniyan maa farada ipa ti ayipada òju ọjọ kó ni ìṣilọ[6].

Awọn Ìtọkasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Migration and global environmental change: future challenges and opportunities". GOV.UK. 2011-10-20. Retrieved 2023-09-21. 
  2. Ghosh, Pallab (2011-10-20). "Climate change migration warning issued through report". BBC News. Retrieved 2023-09-21. 
  3. Rosner, Hillary (2011-10-20). "Millions Will Be Trapped Amid Climate Change, Study Warns". Green Blog. Retrieved 2023-09-21. 
  4. "Alert sounded on ‘environmental migration’". Financial Times. Retrieved 2023-09-21. 
  5. Migration and global environmental change: final project report. The Government Office for Science, London. 2011. pp. 67. 
  6. Migration and global environmental change: final project report. London: Government Office of Science. 2011. pp. 137.